Ikorodu cult crisis: A máa gbé Orò síta lọ́jọ́kọ́jọ́ tí ìjà ẹgbẹ́ òkùnkùn bá tún ṣẹlẹ̀- Àwọn Oba ní Ikorodu
Ọ̀pọ̀ awọn ọdọ to n yọ Ikorodu lẹnu lo ni Baba Isalẹ ninu oṣelu- Oba
Lori ikọlu to n waye lojoojumọ ni agbegbe Imọta, Agbowa ati Ibo miran ni Ikorordu lo jẹ ki BBC Yoruba jade lọ wadi ohun ti o n ṣokunfa ilu o fararọ nibẹ.
- Kí ló ń fa rúgúdù láàrín àwọn òṣìṣẹ́ fásitì EKSU àti ìjọba Ekiti?
- Wo ìpínlẹ̀ 14 ní Nàìjíríà tí America kílọ̀ pé kí àwọn eèyàn rẹ̀ má dé ...
- Kíni ìdí ti àwọn ọmọ ogun fi n ṣọ́ àwọn Imaam ni Mecca?
- Wo ìdí tí ìjọba Buhari fi dúró gìdìgbà lẹ́yìn Pantami t'áráàlú ní kó fipò sílẹ̀
- Dangote àti iléeṣẹ́ méjì ló ń ta símẹ́ntì, ìjọba gbọdọ̀ wá ńkan ṣe sí ọ̀wọ́n-gógó yìí- Aṣòfin
- Irọ́ lásán ni pé èèyàn 25 bọ́ sọ́wọ́ ajínigbé ní òpópónà Igboọra sí Eruwa - Ọlọ́pàá Ọyọ
Ninu ifọrọwerọ pẹlu awọn Oba alade ni agbegbe yii ati pẹlu awọn ar ilu ni BBC ti fidiẹ mulẹ pe ọrọ naa ko ṣẹyin emi ni mo ju ẹ, iwọ lo ju mi laarin ẹgbẹ okunkun.
Awọn Oba Alade ni ẹkun yii bu ẹnu ẹ̀tẹ́ lu iwa jagidijagan laarin awọn ọdọ naa.

Oba Ganiyu Aderibigbe Jamade 1 sọrọ ilẹ kun lori ona abayọ si iṣoro to n koju eto aabo ni ẹkun yii.
Bakan naa ni Oba Mudashiru Ajibade to jẹ Ranodu ti Imọta naa sọ ero tirẹ.
Wọn ni Ainiṣẹlọwọ lo n yọ ọdọ Ikorodu lẹnu nitori ko si nkan ti ko le lo ọwọ to ba dilẹ.
- A ti wà nínú igbó láti ṣàwárí àwọn mẹ́ta tí wọ́n jí gbé ní Ikaramu Akoko - Amotekun Ondo
- Ṣé òtítọ́ ni pé ikú apanilẹ́ẹ̀rín Ada Jesus lọ́wọ́ ayé nínú?
- Mo ti di 'Millionaire' kí n tó pé 18 rárá, ìdí iṣẹ́ arìnrìnoge ni mo ti di òṣèré- Omotola Jalade Ekeinde
- Wo àwọn 'App' tó ń ba fóònù jẹ́ ní Nàìjíríà
- Wọ́n ti sin òkú àwọn èèyàn tó lé ní àádọ́ta tí àwọn agbébọn pa ní Zamfara báyìí
- Ṣé lóòtọ́ọ́ ni ibi ọmọ níí ṣe pẹ̀lú àyànmọ́ ọmọ láyé? Kínni pàtàkì ibi ọmọ?

Koda, wọn tun ni awọn Oloṣelu naa n fi kun nkan to n ṣẹlẹ nitori pe bi agbofinro ba ti mu awọn ọdọ oni ipanle yii ni wọn lọ n agb wọn silẹ pe 'Boys wa ni wọn".
BBC tun ba awọn to ti faragba ninu iṣẹlẹ yii sọrọ ti ẹbi wọn ti ku tabi farapa nibẹ sọrọ.
Wọn sọ ohun ti oju wọn n ri ti ọkan ara ilu ko balẹ mọ.
