Oladele Ogbeyemi Albert: Irin tí mò ń lò máa ń bá mi sọ̀rọ̀ nínú ẹ̀mí kí ń tó gbẹ́ wọn sóhun tó wù mí
Gbogbo igba ti mo ba ti n ri iṣẹ mi ninu mi maa n dun yatọ- Oladele Ogbeyemi Albert
Agbegilere jẹ ọkan lara iṣẹ adayeba Yoruba lati aye atijọ ṣugbọn bayii awọn ọmọ Oodua ti n fi irin da ara to wu wọn.
- Agbaṣẹ́ṣe jẹ búlálà méjìlá lẹ́yìn tó jí ẹ̀rọ ìbáraẹnisọ̀rọ̀
- Ta ló sánwó ilé ìwòsàn Sóò bàtà Yorùbá tó dá sọ́rọ́ aláboyún ní Sasa?
- Ìrọ́ ní ò, a o fí ìgbà kankan fí Olupelumi Fagboyegun, Ìbátan Akeredolu sí ẹ̀wọ̀n- Iléẹ́jọ́ ìpínlẹ̀ Ondo
- Ọmọ Nàìjíríà Invictus Obinwanne Okeke rẹ́wọ̀n ọdún mẹwàá he l'Amerika lórí ẹ̀sùn jìbìtì $11m
- Ọwọ́ tẹ Sani fọganáísà tó fipá bá ọ̀dọ́mọbìnrin ẹni ọdún 15 lò pọ̀ tó fi kú
Oladele Ọgbẹyẹmi Albert ree ti o n ṣiṣẹ agbẹ iri ni ere ni Naijiria.
Odọmọkunrin yii sọ fun BBC Yoruba pe lati ọdun 2013 loun ti yan iṣẹ naa laayo.

O kọ si i nipa rẹ ni Universal studio of Art ko to tun lọ si Yaba College of Technology ni ipinlẹ Eko ni Iwọ oorun guusu Naijiria.

Oladele Albert menuba awọn aṣeyọri ati ami ẹyẹ to ti gba ni Naijiria tai ni oke okun lẹnu iṣẹ agbẹirin ni ere yii.
- Ọwọ́ tẹ Sani fọganáísà tó fipá bá ọ̀dọ́mọbìnrin ẹni ọdún 15 lò pọ̀ tó fi kú
- Wo àwọn ohun méje tó yẹ kí o mọ̀ nípa Ngozi Okonjo-Iwealla àti ọkọ rẹ̀ Ikemba
- Wo ohun 10 tó yẹ́ kó mọ̀ nípà Ọ̀gà EFCC, Abdulrasheed Bawa tí ààrẹ̀ Buhari yàn
- Kíní ìtumọ̀ àyájọ́ Ọ̀jọ ''Ash Wednesday' tó wáyé lóní?
- Gómìnà ìpínlẹ̀ Kano ṣèrànwọ́ ₦18.5m fún àwọn ọmọ ìpínlẹ̀ rẹ̀ tó faragbá nínú rògbòdìyàn tó wáyé ní Sasa
O ni ẹranko ni oun yan laayo julọ lati maa fi irin da ara to wu oun le lori nitori pe oun fẹran ẹranko pupó.

Albert mẹnuba iwuri rẹ ati afojusun rẹ fun ọjọ ọla.
O ni oun fẹ jẹ iwuri ati awokọse rere fun awọn ọdo Naijiria.

Bakan naa ni Oladele Albert Ogbeyemi sọ nipa ipenija ẹnu iṣẹ naa.




