Orlando Owoh: Ayé ti sú mi, àdúrà ikú ìrọ̀rùn ló wù mí- Christiana, Ìyá Orlando Owoh tó ti pé ọdún 110
Wo itan igbe aye Orlando Owoh nibi
A bi Stephen Oladipupo Owomoyela ni ilu Osogbo ni ipinlẹ Osun ni guusu Iwo oorun Naijiria ni ọjọ kẹrinla, oṣu kejì, ọdun 1932 ṣugbọn ọmọ ipinlẹ Ondo ni.
Christiana Morenike Owowmoyela ati baba rẹ Owomoyela lo bii ti wọn si jẹ ọmọ Owo ati Ifon ni ipinlẹ Ondo.

Odun 1960 ni o da ẹgbẹ olorin rẹ sile eyi to pe ni Orlando Owoh and his Omimah Band.
Orlando Owoh jade laye lọjọ kẹrin, oṣu kọkanla lọdun 2008.
Oni lo pe ọdun mejila ti Orlando Owoh, agba ọjẹ onkọrin ni di ara ọrun.
BBC Yoruba lọ si ilu Ifọn nibi ti iya Orlando Owoh n gbe lati kan si ẹbi rẹ.
Orlando Owoh fun mi ni okiki pupọ nigba aye rẹ- Christiana Iya Orlando Owoh
Mo mọ bi Orlando ṣe jiya bẹrẹ iṣẹ orin ṣugbọn nkan pada yipada si rere ki ọlọjọ to de- Lola Okoh to jẹ aburo Orlando Owoh
- Kìí ṣe gbogbo ohun tí dókìtà ni kí n má jẹ torí àìsàn jẹjẹrẹ ni mo tẹ̀lé- Soyinka
- Ẹ dẹ̀kun lílo Sniper àti Dichlorvos fún ìtọ́jú oúnjẹ- NAFDAC kìlọ̀
- Wo ọ̀nà àbáyọ fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tí àjọ WAEC gbẹ́sẹ̀ lé èsì ìdánwò wọn
- ''Àjọ NERC ti fún Disco láṣẹ láti padà sí owó tàríìfù tuntun iná mọ̀nàmọ́ná''
- EFCC bẹ̀rẹ̀ ìwádìí lórí ẹ̀sùn ìwà jẹgúdújẹrá tí wọ́n fi kan Fowler tó jẹ́ Alága iléeṣẹ́ FIRS tẹ́lẹ̀
Èmi àti Oladipupo Owomoyela jọ lọ ẹ̀wọ̀n Alágbọn- Caroline Owoh, aya Orlando Owoh
Sunny Ade maa n ko 'Gloves' ti Orlando Owoh fi n ja ẹṣẹ tẹlee ni nigba aye rẹ - Folarin Ogunmolawa aburo Orlando Owoh

Caroline Owomoyela to jẹ aya Orlando ni: A jọ lọ ẹwọn ni alagbọn a tun jọ de pada de sile ni
Koda a ko gbagbọ pe Orlando Owoh ku, a fi bii ala.
- ''Àjọ NERC ti fún Disco láṣẹ láti padà sí owó tàríìfù tuntun iná mọ̀nàmọ́ná''
- EFCC bẹ̀rẹ̀ ìwádìí lórí ẹ̀sùn ìwà jẹgúdújẹrá tí wọ́n fi kan Fowler tó jẹ́ Alága iléeṣẹ́ FIRS tẹ́lẹ̀
- Wo ǹkan tó yẹ kí o mọ̀ nípa Joe Biden, tó ń kojú Trump nínú ìbò America
- Kíní ọ̀nà àbáyọ sí ìjàmbá ọkọ̀ tó ń wáyé lemọ́lemọ́ ní Ọjà Akungba,ní Ondo?
- 'Ìdí tí kámẹ́rà táa rí ní Lekki Tollgate kò fi ká gbogbo ìṣẹ̀lẹ̀ tó wáyé rè é'

Iya Orlando Owoh ti pe ẹni ọdun aadọfa bayii.
O ni: mi o kọkọ fọwọ si iṣẹ orin ti Orlando n kọ nibẹrẹ ṣugbọn inu mi dun si okiki to mu wa fun mi ati ogo gbogbo idile.

Àwọn ẹbi sọrọ nipa iwa ikonimọra ti Orlando ni.
BBC tun de oju oori Orlando Owoh.
Aya rẹ ti wọn jọ ṣẹwọn ni alagbọn sọrọ ni kikun.
Kunle Orlando Owoh, ọkan lara awọn ọmọ rẹ to n kọrin bayii sọrọ nipa imọran ti baba rẹ n fun un nigba aye rẹ.
- EFCC bẹ̀rẹ̀ ìwádìí lórí ẹ̀sùn ìwà jẹgúdújẹrá tí wọ́n fi kan Fowler tó jẹ́ Alága iléeṣẹ́ FIRS tẹ́lẹ̀
- Kíní ọ̀nà àbáyọ sí ìjàmbá ọkọ̀ tó ń wáyé lemọ́lemọ́ ní Ọjà Akungba,ní Ondo?
- Wo àfipábánilòpọ̀ ẹni ọdún 51 tí ìjọba ìpínlẹ̀ Ekiti tú làṣirí ní gbangba
- Ẹ fún wa lówó oṣù wa tàbí kí a gùnlé ìyanṣẹ́lódì ọlọ́jọ́ gbọọrọ- Àwọn dokita ìpínlẹ̀ Ondo
- Ilé aṣòfin ìpínlẹ̀ Oyo jáwée lọ sinmi nílé fún alága ìgbìmọ̀ mẹ́tàlá káàkiri ìjọba ìpínlẹ̀
- Wo ǹkan tó yẹ kí o mọ̀ nípa Joe Biden, tó ń kojú Trump nínú ìbò America


