EndSARS, EndSWAT Protests: Òbí agbábọ́ọ̀lù Kazim Tiamiyu Kaka àtàwọn míì tí ọlọ́pàá pa sọ̀rọ̀, omijé bọ́ lójú

Àkọlé fídíò, EndSars, EndSwat Protest: Òbí agbábọ̀ọ̀lù Gbenga Tiamiyu Kaka àtàwọn míì tí ọlapàá pa sọ̀r

Kàyééfì tuntun rèé lórí #EndSARS, ọ̀rọ̀ pọ̀ nínú ìwádìí BBC

Mi ò gbọdọ̀ fojú rí ẹni tó wọ aṣọ SARS; òkú méjì a bá Olorun nílé ni- Iya Kaka Tiamiyu

Aseyori ikọ SARS akọkọ ni Eko ni wọn fi tan wọn kalẹ Naijiria

Iwa ibajẹ, idunkooko mọ ni ati bẹẹ bẹẹ lọ lo sọ awọn oṣiṣẹ SARS di ari ma dun nu si fun ọpọ ọmọ orilẹ-ede Naijiria.

Mi o gbọdọ fi oju ri ẹni to wọ aṣọ SARS; Oku meji a ba Olorun nile ni- Iya Agbabọọlu tiamiyu Kazzim Kaka

Inu mi maa n bajẹ ni ti mo ba ti ri SARS- Baba Kaka Tiamiyu Kazim

Fasasi Tiamiyu to jẹ baba rẹ naa sọrọ ilẹ kun pe o wu oun lati foju kan Niyi Ogunsoro ti ọpọ n pe ni O yatọ to jẹ ọlọpaa SARS ti awọn alafojuri ni o pa ọmọ wọn.

Iya Kaka

Toluwani Awakan ati awọn ẹbi awọn mii bii Kolade Johnson atawọn ti iroyin tun ni awọn ọlọpaa SARS pa naa sọrọ to pọ.

wo awọn ohun ti SARS fi n ṣe ami idanimọ ọdọ ti wọn ba ni o n ṣe yahho yahoo.

Fasasi Tiamiyu, Baba Kaka