Alaafin Oyo's wives: Wo ohun tó yẹ kí o mọ̀ nípa olorì Alaafin Adeyemi àkọ́kọ́, ayaba Abibat Nihinlola Adeyemi

Oríṣun àwòrán, olori_omoh_one
Leyin ti Oba Lamidi Adeyemi waja tan ni awọn eeyan ti n beere nipa olori akọkọ ni ẹ̀ẹ̀dẹ̀ Kabiesi.'Ètò ayẹ́yẹ́ ìsìnkú Oba Lamidi Adeyemi kòí tíì wáyé, àfọ̀mọ́ Aàfin ń lọ lọ́wọ́'
Bẹ́ẹ̀, Oba Atanda Olayiwole gbiyanju laye ki awọn alalẹ̀ to pe Iku Baba Yeye sódó pe ki Baba pa ipo da.Wo bí àwọn Alfa ṣe kírun sí Aláàfin lára àti ètò tó kàn láti gbé e wọ káà ilẹ̀
Ojọ́ Abameta, ọjọ ketalelogun, osu kerin, ọdun 2022 ni Oba Lamidi Adeyemi kẹta dagbere faye pe o digbose.Òrumọ́jú ní ara Oba Lamidi Adeyemi wọ káà ilẹ̀ lọ ní Báárà gẹ́gẹ́ bí ìṣe ìran Yorùbá ṣe làá kalẹ̀
- Nínú àwòràn, wo ìgbà ayé Aláafin Oyo, Ọba Lamidi Adeyemi kẹta tó lọ bá àwọn Baba Ńlá rẹ̀
- Ta ni Yorùbá ń pè ní Abọ́bakú?
- Aláàfin àti Ọba ilẹ̀ Yorùbá márùn-ún mìí tó wàjà láàrin oṣù márùn-ùn péré
- Wo àwọn ǹkan tí o kò mọ̀ nípa Ọba Lamidi Adeyẹmi, òṣìṣẹ́ adójútòfò àti Abẹ̀ṣẹ́kùbíòjò tó wàjà
- Ààrẹ Buhari, Ooni Ile Ife, Obasanjo kẹ́dùn Alaafin Oyo tó wàjà
Bawo ni Olori Nihinlola Abibat Adeyemi se de Aafin?
Kii ṣe ohun aṣiri pe Eledua fi ọpọ aya kẹ Kabiesi, Alaafin ilu Oyo, Ọba Lamidi Olayiwola Adeyemi.Wo Alàáfin 43 tó jẹ́ láti ìgbà ìwásẹ̀ ṣáajú Lamidi Adeyemi tó ṣẹ̀ṣẹ̀ wàjà
Amọ ayaba Abibat Nihinlola Adeyemi ni aya rẹ akọkọ, awọn mejeji si ti wa gẹgẹ bii tọkọ-taya lati nnkan bii ọgọta ọdun titi di asiko yii.Kéte ti Baba dákẹ́ ni àṣà àti ìṣẹ̀ṣe ti bẹ̀rẹ̀ l'Áàfin - Ẹ wo ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ohun tó ń ṣẹlẹ̀ ní Aafin Oyo
Iya Adodo, gẹgẹ bi wọn ṣe maa n pe olori naa kii kan n ṣe aya Alaafin lasan, oun ni ẹni ti ọpọ awọn to sun mọ ori Ade naa mọ gẹgẹ bii igi lẹyin ọgba Kabiesi.
- Olòrì Silekunola Naomi Ogunwusi: Mo ti sún síwájú, mo gbìyànjú pé kí ìgbèyàwó yìí ṣiṣẹ́ ṣùgbọ́n....
- Ìjọba Osun jáwe lọ rọọ́kún nílé fún olùkọ̀ nítorí pé ó sọ̀rọ̀ tako ìjọba lórí Facebook
- Mọ̀ síi nípa Bola Ige tó jẹ́ mínístà ètò ìdájọ́ ṣùgbọ́n tí wọ́n ṣì ń wá ìdájọ́ òdòdo lórí ikú rẹ̀
- Kò tíì pẹ́ jù bí ìjọba bá leè sọ ẹni tó pa olóògbé Bola Ige- Gani Adams
- Kí ló dé tí Ooni Ile Ife fẹ́ gbẹ̀mí ara rẹ̀?
- Àìsàn tó ń ṣe ọ ní ohun ṣe pẹlú oorun rẹ - Onímọ
- Kí ló dé tí Hisbah Kano ṣe fìwé pe Òbí Shatu Garko tó ṣẹ̀ṣẹ̀ jẹ 'Miss Nigeria'?
Gẹgẹ bii ohun ti a gbọ, Alaafin ni atilẹyin olori naa to bẹẹ to fi jẹ pe oun lo gba Alaafin nimọran lati fẹ iyawo tuntun.
Lonii, iyawo Alaafin ti le ni mejidinlogun.
Iroyin ni Alaafin gbe ayaba Abibat niyawo lasiko ti olori naa wa ni ọmọ ọdun mẹtadinlogun lẹyin ti awọn mejeji pade nipasẹ aburo Alaafin to jẹ akẹgbẹ ayaba nile ẹkọ kan naa lọdun 1956.

Oríṣun àwòrán, Iwo odidere
Tani Olori Abibat Adeyemi?
Iyẹn ṣaaju ki Alaafin ti gori itẹ awọn baba rẹ lọdun 1970.
O tẹlẹ Alaafin lọ silu Eko nibi to ti ṣiṣẹ diẹ, o tun kọ iṣẹ ranṣo-ranṣọ, ti Ọlọrun si fi ọmọ mẹta ta awọn mejeji lọrẹ.
Gbogbo awọn ọmọ ti ayaba naa bi fun Kabiesi lẹyin awọn mẹta naa ni wọn ti dagba bayii, wọn si yan, wọn yanju.
Ọjọ ori kan naa ni ayaba Abibat ati Alaafin Oyo, ṣugbọn kii ṣe oṣu kan ni wọn bi wọn.
Ọjọ kẹtalelogun, oṣu Kejila, ọdun 1938 ni wọn bi ayaba Abibat.

Oríṣun àwòrán, olori_omoh_one
Wọn si bi si idile Laguna, ni adugbo Agunpopo, niluu Oyo.
Ayaba yii kan naa lo bi ọmọ okunrin ati obinrin akọkọ ti Ọlọrun fi ta Alaafin lọrẹ.
Adura wa ni pe ki Ọlọrunnlọra Kabiesi ati Ayaba Abibat Adeyemi.














