Àwọn ọmọ Nàìjíríà bínú sí olóngbo àti ẹlẹdẹ to sọ àsọtẹlẹ

Oríṣun àwòrán, Reuters
Ati ẹni tó sọ àsọtẹlẹ ati awọn tó gbà a gbọ, ojú wọn ti já a bayii pẹlú bí Argentina ti ṣe ràn ìkọ Super Eagles pada wale ninu ìdíje àgbáyé.
Kí a gbaju mọ nkan mi kọ́ lọrọ kan bayi?
Àwọn èèyan kàn ni ko ri bẹẹ.
Won ní dandan, dandan olóngbo àti ẹlẹdẹ to sọ àsọtẹlẹ pé ìkọ Super Eagles yóò pegede nínú ìdíje náà gbódò wá salaye bi ọrọ se gba ọ̀nà míì yọ.
L'oju òpó Twitter, nise ní àwọn iriwisi oríṣiríṣi lórí aṣemáṣe awọn eranko wọn yi ti n wáyé.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 1

End of X post, 2
Sugbọn awọn kan ni kii se ẹbi olóngbo àti ẹlẹdẹ ni kan.
Wọn ni Odion Ighalo, atamatase fún ìkọ Super Eagles to ko lati jẹ goolu naa fara ko ninu ẹbi ọrọ́ yii.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 3

End of X post, 4
Olùdarí ifẹsẹwọnsẹ orí pápá bákan náà to je ọmọ orílèèdè Turkey ti ri ìbínú awọn ololufẹ Super Eagles.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 5

End of X post, 6
Awọn kan ni ọna ati pa ironu rẹ́ ni ìgbé ti awọn ọmọ orílèèdè Nàìjíríà n pa lójú òpó Twitter lẹyìn tí ìkọ Super Eagles fidiremi nínú ìdíje àgbáyé.
Sugbọn o jẹ oun to n pani lẹrin.
Argentina gbo ewuro soju awọn ikọ Super Eagles pẹlu bi wọn ti ṣe rán Naijiria pada sílé.
Ayọ méjì ṣọkan ní wọn fi fakoyo ninu ifẹsẹwọnsẹ tó wáyé lọjo ìṣẹgun.