Kiki Osinbajo: Tó bá yá owó lọ́wọ́ ẹnikẹ́ni, máa gbìyànjú láti da padà

Àkọlé fídíò, Kiki Osinbajo: T;o bá yá owó lọ́wọ́ ẹnikẹ́ni, máa gbìyànjú láti da padà

Kiki Osinbajo, tii se ọmọ igbakeji aarẹ Yemi Osinbajo ti salaye fun BBC Yoruba nipa awọn ọna ti eeyan fi le lo ori ayelujara lati mu ki okoowo gbooro si.

Bakan naa lo sọrọ lori awọn ipenija tawọn ọdọ Naijiria n koju ninu isẹ ati okoowo wọn, to si fi awọn iriri to ti la kọja bii olokoowo se apẹrẹ.

Ko tan sibẹ, Kiki tun sọrọ nipa ọna to gba bẹrẹ okoowo ati ipenija to n koju awọn obinrin aye ode oni.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: