Tọkọ-tayà Osinbajo kò gbẹ́yìn níbi ayẹyẹ ọjọ́ ìbi Folu Adeboye Oríṣun àwòrán, Rccg/twitter
Àkọlé àwòrán, O ni àwọn ise ìrànwọ ti ó ń wọn se fawọn ọ̀dọ́ àti àwọn alaini kò lẹ́gbẹ́ 14 Agẹmo 2018
Ìyá Adeboye jẹ́ àwòkọ̀ṣe rere fàwọn obínrin ìwòyí
Igbakeji ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Ọjọgbọn Yemi Osinbajo, tí dáwọ̀ọ́ ìdùnnú pẹ̀lú ìyàwó adari ìjọ ìràpada (Redeemed Christian Church of God), Olusọaguntan Folu Adeboye.
Oríṣun àwòrán, Osinbajo/twitter
Àkọlé àwòrán, Osinbajo dúpẹ́ lọ́wọ́ Mummy G.O, Folu Adeboye bí ó ṣe jẹ àwokọṣe fún àwọn obinrin
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ sí: Oríṣun àwòrán, Osinbajo/twitter
Àkọlé àwòrán, O ni àwọn ise ìrànwọ ti ó ń wọn se fawọn ọ̀dọ́ àti àwọn alaini kò lẹ́gbẹ́. Osinbajo ní ó jẹ́ ohun ìdunnu lati ni iru arabinrin Folu Adeboye lawujọ àwọn obínrin gẹgẹ bíi oniwàásù àti àwokose fawọn obinrin.
Ó rọ awọn obinrin lati ni suuru pẹ̀lú ẹbí wọn lai faaye gba iwa ipá ninu ile ati lawujọ pẹlu afiwe Iya Adeboye.
O ni àwọn ise ìrànwọ ti Iya Adeboye ń se fawọn ọ̀dọ́ àti àwọn alaini kò lẹ́gbẹ́.
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Play video, "Fọlọrunṣọ Alakija: Imọ ṣe koko", Duration 1,40 01:40 Àkọlé fídíò, Wo imọran Fọlọrunṣọ Alakija fun awọn ọdọ adulawọ Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Play video, "'Obinrin jẹ amuludun'", Duration 1,15 01:15 Àkọlé fídíò, 'Obinrin jẹ amuludun' Igbákeji ààrẹ, Ọjọgbọ́n Yemi Osinbajo gbadura kí Ọlọrun túbọ̀ lọ́ra ẹ̀mí wọn
Oríṣun àwòrán, Osibajo/twitter
Àkọlé àwòrán, O ni àwọn iṣẹ́ ìrànwọ́ ti ó ń se fawọn ọ̀dọ́ àti àwọn alaini kò lẹ́gbẹ́. Arabìnrin Folukẹ Adeboye pe ọmọ ààdọrun ọdún lori oke eèpẹ̀ lánàá.
Opọlọpọ eto ni awọn eniyan ṣe lati fi sami ayẹyẹ ọdun rẹ ti awọn èrò pupọ si n ki olukọ ati oniwaasu naa lori ayelujara kaakiri agbaye.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Play video, "‘Awọn ọlọpaa n yin tajutaju fun wa’", Duration 1,04 01:04 Àkọlé fídíò, Ekiti Election: Awọn oludibo ko mọ idi ti wọn fi n yin tajutaju ni Okesha Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Play video, "Adun Ọbẹ Ẹgusi", Duration 2,20 02:20 Àkọlé fídíò, Ọbẹ Ẹgusi sise ati jijẹ Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Play video, "'Ọlọ́run ló pè èmi Fẹmi Adebayo sí òṣèlú'", Duration 2,38 02:38 Àkọlé fídíò, Femi Adebayo: Ẹyin ọ̀dọ́, ẹ káàbọ̀ ságbo ilé Tíátà