Àwọn àwòrán tó ṣé àfihàn Osinbajo lẹni tí kò mú ayé le

Wọ̀nyìí ni àwòrán oríṣiríṣi to se àfihàn Ọjọgbọn Oníwàásù to di olóṣèlú, ìgbákejì Ààrẹ Yemi Osinbajo gẹgẹ bí ẹni tó já síi

Igbakeji Aare Yemi Osinbajo

Oríṣun àwòrán, @hmkstudious_ng

Àkọlé àwòrán, Àwòrán Osinbajo yí ní ilé oúnjẹ kàn labuja wà lára àwọn àwòrán Osinbajo tó kọ́kọ́ mú kí àwọn ọmọ Nàìjíríà fẹràn rè
Igbakeji Aare Yemi Osinbajo

Oríṣun àwòrán, @ProfOsinbajo

Àkọlé àwòrán, Ẹ jẹ kí ọmọdé wà. Igbákejì Ààrẹ Yemi Osinbajo a máa bà àwọn ọmọdé ṣeré níbikíbi tó bá tí pàdé wọ́n.
igbákejì Ààrẹ Yemi Osinbajo

Oríṣun àwòrán, @ProfOsinbajo

Àkọlé àwòrán, Àwọn obìrin náà a máa du igbákejì Ààrẹ Osinbajo ṣùgbọ́n............
Igbakeji Aare Yemi Osinbajo

Oríṣun àwòrán, ProfOsinbajo

Àkọlé àwòrán, ọrọ̀ ìfẹ bí àdánwò ní. Dolapo Osinbajo nìkan ní ẹní ọkàn ìgbákejì Ààrẹ Osinbajo yan láàyò.
Igbakeji Aare Yemi Osinbajo

Oríṣun àwòrán, @ProfOsinbajo

Àkọlé àwòrán, Èkùrọ́ lalá bákú ẹ̀wà; àwọn méjèjì a máa tage ìfẹ lóòrèkóòrè.
Igbakeji Aare Yemi Osinbajo

Oríṣun àwòrán, @ProfOsinbajo

Àkọlé àwòrán, ''AyanYemi ọmọ Ayanbajo''. Ẹní mú kóngò dání ló mò èdè àyàn. Ayanyẹmi nikan lo mọ ohun to n fi omele sọ
Igbakeji Aare Yemi Osinbajo

Oríṣun àwòrán, @ProfOsinbajo

Àkọlé àwòrán, Àwọn eléré ìdárayá jẹri síi pé Osinbajo mo bí nnkan ṣé n ló ní ìgboro
Igbakeji Aare Yemi Osinbajo

Oríṣun àwòrán, @ProfOsinbajo

Àkọlé àwòrán, N gbó Olamide...bawo lo ṣé n ló ní ìgboro ẹyin ọ̀dọ́?
Igbakeji Aare Yemi Osinbajo

Oríṣun àwòrán, @ProfOsinbajo

Àkọlé àwòrán, Ọmọ kìí dàgbà lójú òbí ré, ìyá ni wúrà iyebiye ti a kò le fi owó rà
igbákejì Ààrẹ Yemi Osinbajo

Oríṣun àwòrán, @ProfOsinbajo

Àkọlé àwòrán, Osinbajo a máa tẹti gbọrọ. O ṣàlàyé pé Baba yí tí òun pade ni Yewá lè ma je Bàbá to bi òun ṣùgbọ́n òun mo iyì àgbà.