Buhari meets with senators: Ààrẹ Buhari ń ṣèpàdé pẹ̀lú àwọn sẹ́nétọ̀ 109 lálẹ́ ọjọ́ Iṣẹ́gun

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Ààrẹ Muhammadu Buhari yoo sepade lalẹ ọjọ Isẹgun pẹlu awọn seneto Naijiria mokandinlaadota pẹlu jije ounje ale pò nílé ààrẹ l'Abuja.
Ìkede ipàdé yìí tí yóò kó awon asofin ile igbimo asofin agba ati Asoju sofin jade ninu leta ti ile asofin ko eyi ti aare ile asofin agba, Ahmed Lawan ka sì eti igbo gbogbo ile.
- 'Restructuring' la fi ta Buhari fún ìran Yorùbá, ṣùgbọ́n ó dùn mi pé irọ́ ni Buhari pa- Olagunsoye Oyinlola
- Àwọn oníṣẹ̀ṣe ń fẹ́ kí ìjọba yọ ọwọ́ nínú Ọba yíyàn ní ìpínlẹ̀ Ogun
- Mi ò lè fọwọ́ sí àbáòfin kankan tí yóò fòfin de iṣẹ́ akọ̀ròyìn - Femi Gbajabiamila
- Irọ́ ni o! Awujale ilẹ̀ Ijebu kò wàjà, ẹ sinmi ariwo
- A gbọ́dọ̀ fi àwọn olùwọ́de Yorùbá Nation sí àhámọ́ fún ọjọ́ 21, bí bẹ́ẹ̀ kọ́.....- Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Eko
- Ọkùnrin márùn-ún tí wọ́n bá lórí kerewà bọ́ sọ́wọ́ Ọlọ́pàá ẹ̀sìn Islam
Ni ojo ketadinlogbon osu kerin ni awon asofin fẹnuko pe kí adari ile ṣe eto ipade náà láti jo jiroro lori oro abo to n ba Naijiria fúnra.
Leta naa ka pe "mo n kọ ìwé yìí láti sí aare ile igbimo asofin agba pe aare Muhammadu Buhari yóò se Ipade pelu awon seneto Naijiria ni ojó Isegun, ojo ketala osu keje odun 2021 ni dede agogo mejo ale.
Ìpàdé yìí ni ìròyìn ni yóò wáyé ní gbongan apeje ni ile aare to wa ni Abuja.
Ẹ o maa ri ẹ́kunrẹrẹ iroyin nipa ipàde naa ka nibi to ba ti waye.
- Ìjọba ìpínlẹ̀ Kaduna kéde òní ọjọ́ Ajé gẹ́gẹ́ bíi ọjọ́ ìsinmi nítorí ikú ìgbákejì gómìnà Bantex tó dolóògbé
- Wo ohun tí TuFace, Mr Macaroni àti DJ Cuppy sọ nípa Sound Sultan
- Kí gbogbo ilé ìjọsìn Eko padà sí ìlàjì iye ènìyàn tó lè wa jọ́sìn- Sanwo Olu
- Àlúfà S.K. Abiara sọ̀rọ̀ nípa ìgbésí-ayé T.B. Joshua níbi ìsìn ìdúpẹ́








