Olugbon of Igbon: ‘Rubber Stamp’ làwọn aṣòfin àpapọ̀, wọn kò ṣojú aráàlú
Olugbon tile Igbon, Ọba Francis Olusola Alao ti kede pe oun n siyemeji nipa aarẹ Buhari to wa nipo nitori kii se Buhari toun mọ lọdun 1983 ree.
Kabiyesi, ẹni to woye ọrọ yii lasiko to n fọrọwerọ pẹlu BBC Yoruba tun woye pe awọn asofin agba ko lọ soju araalu, wọn kan wa nibẹ bii fidi hẹẹ ni.
Ọba Alao ni agbara ti pọ ju lọdọ ijọba apapọ, o si yẹ ki gbogbo ẹya to wa ni Naijiria joko lati wa bi atunto yoo se ba orilẹede yii.
- Wọ́n ti ń ti ọ̀rọ̀ olóṣèlú bọ ọ̀rọ̀ Sunday Igboho ní èyí tó yẹ kí Yorùbá fi ṣọ́ra- Oba Francis Olusola-Alao
- Òpùrọ́ ló pọ̀ nínú àwọn oníṣẹ̀ṣe, olóòtọ́ọ́ wọn ṣọ̀wọ́n - Olugbon
- Wo nọ́mbà ìpè pàjáwìrì tíjọba Oyo fi síta fún ẹni tó bá wà nínú ewu
- Alao Akala ló da ìgbìmọ̀ lọ́balọ́ba Oyo rú, àwa ọba kò jìjà àgbà - Onpetu Ijeru
- Ìyàtọ tàbí àfiwé wo ló wà láàrin Sunday Igboho, Nnamdi Kanu àti Asari Dokubo?
- Kìí ṣe nítorí mi ò ṣ'ètùtù ni olorì méjì ṣe kú, àsìkò wọn ló tó- Oba Onpetu
Bakan naa tun ni oriade yii ke si gomina Seyi Makinde tipinlẹ Oyo lati tubọ tẹmpẹlẹ mọ ipese eto aabo to pegede bi o tilk jẹ pe o n gbinyanju.
O ni aidangajia ijọba apapọ nidi ipese eto aabo to peye lo mu kawọn ijọba ipinlẹ nilẹ Yoruba da ikọ alaabo Amotekun silẹ, o si ni awọn naa n gbinyanju.
Àwọn ìtàn mánigbàgbé tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Ìdílé márùn-ún tó gbajúmọ̀ fún òwò ẹrú nílẹ̀ Yorùbá
- Ìtàn ayé Ọba Seriki Abass ti Badagry, tó ní aya 128, ọmọ 144
- Ìtàn rèé nípa bí Ogbomoso ṣe pa ọba, yọ nǹkan ọkùnrin rẹ jó kiri ìlú
- Àwọn ọba Yorùbá kan rèé tí wọ́n rọ̀ lóyè, tí ọba míràn jẹ lójú ayé wọn
- Kí ló fà ogun Ìjàyè àti ìṣubú Kurunmi, ìfẹ́ ìlú ni àbí orí kunkun?
- Duro Ladipọ, ìlúmọ̀ọ́ká òṣèré tíátà àti ọmọ àlúfà tí kò gbàgbé àṣà ìbílẹ̀
- Ìtàn ìgbésí ayé Oshodi, ọmọ Tápà léǹpe tó di akọni ní ìlú Eko
- Ìtàn Manigbagbe: Àwọn àjakalẹ-àrun to ti wáyé rí ṣáájú Coronavirus
Ọrọ pọ ti Olugbon ba BBC Yoruba sọ, ẹ sa wa nnkan fidi le lati gbadun fidio yii.




