Oba Sunday Oladapo Oyediran: Alao Akala ní torí Aláàfin kò ṣúgbàá òun fún sáà kejì, ló ṣe pín ipò alága lọ́balọ́ba
Onpetu tilẹ Ijeru, Ọba Sunday Oladapo Oyediran, Lagbami Kẹta ti sisọ loju idi ti omi alaafia igbimọ lọbalọba nipinlẹ Oyo ko se toro.
Bẹẹ ba gbagbe, o ti le ni ọdun mẹwa ti igbimọ lọba lọba ipinlẹ Oyo ti joko sepade nitori aawọ pinpin ipo lọbalọba.
Amọ nigba to n sisọ loju ohun to sokunfa wahala laarin awọn lọbalọba, ti wsn ko fi le joko se ipade fun ọdun pipẹ, Onpetu sọ fun BBC Yoruba pe gomina ana nipinlẹ Oyo, Otunba Adebayo Alao Akal lo fa sababi.
- Áwa Hausa tá a wà l'Ogbomoṣọ ti di Yorùbá- Oba Haruna Sabo Ogbomoso
- Olúwòó ní àwọn Ọba ń se ẹgbẹ́ òkùnkùn
- 'Àwọn agbébọn tó pá Olufon ti Ifon ti ṣe ohun èèwọ̀ ní ilẹ̀ Yoruba'
- Irọ́ ní pé bàbá wa, Soun Ogbomoso paradà di ọmọ tuntun, báyìí ni àwọn ọ̀rẹ́ ṣe dalẹ̀ rẹ̀ tí wọ́n pa á
- Irú ẹ̀dá wo ni Lamidi Adeyemi? Aláàfin tó rí ìbẹ̀rẹ̀ àti opin sáà gómìnà mọ́kànlélógún l‘Oyo
- Wọ́n ti ń ti ọ̀rọ̀ olóṣèlú bọ ọ̀rọ̀ Sunday Igboho ní èyí tó yẹ kí Yorùbá fi ṣọ́ra- Oba Francis Olusola-Alao
- Kìí ṣe nítorí mi ò ṣ'ètùtù ni olorì méjì ṣe kú, àsìkò wọn ló tó- Oba Onpetu
- Mátikú; Oba ìlú Eko tó forí oyè sílẹ̀ lọ́dún 1931 kí àlàáfíà lè jọba
- Mo kọ ìwà ẹlẹ́yàmẹ́yà ló jẹ́ kí ń má a kọ ọmọ Abraka, Ebonyi, Plateau àti Benue nílé ìwé mi lọ́fẹ̀ẹ́- Oba Abolarin
- Àwọn ajínigbé tún ti pé wá lóni ṣùgbọ́n a kò ti rí ìyè owó tí wọn ní ká mu wá-Olori Oba Imope
Onpetu ni Akala ti salaye ninu iwe rẹ to kọ, Amazing Grace nipa idi to fi da ijoko igbimọ lọbalọba naa ru.
Onpetu salaye pe Akala ni nitori pe Alaafin ko se atilẹyin fun oun lati se saa keji lori aleefa, lo mu ki oun se ofin fun pinpin ipo lsbalsba.
O ni Alaka lo se pe ki ipo alaga igbimọ lọbalọba ipinlẹ Oyo jẹ pinpin laarin Alaafin, Olubadan ati Soun, dipo Alaafin to n da nikan wa nipo naa tẹlẹ.
BBC Yoruba tun kan si agbẹnusọ fun Alao Akala, ẹni to ni ọrọ naa ko ri bẹẹ.
Àwọn ìtàn mánigbàgbé tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Ìtàn ayé Henry Fajemirokun, olówó tó fi owó mọ Olúwa àti ènìyàn
- Ìtàn ayé Taiwo Oredein rèé, àgbà òṣèlú tó parí ayé rẹ̀ sọ́gbà ẹ̀wọ̀n
- Wo ìgbẹ̀yìn àwọn ọlọ̀tẹ̀ Yorùbá tó ran Fulani lọ́wọ́ láti kógun ja ìlú Osogbo
- Ìtàn ìgbé ayé Bode Thomas rèé, ó kọ́ wa láti máa kó ẹnu wa ní ìjánu
- Ṣo mọ̀ pé J.F Odunjo jẹ aṣòfin àti mínísítà nílẹ̀ yìí, yàtọ̀ sí pé ó jẹ́ òǹkọ̀wé?
- Ìtàn Àrọ̀gìdìgbà jẹ́ kí ń rò pé bàbá mi yan Yemọ̀ja ní àlè - Ọmọ Fagunwa
Bakan naa, ninu ifọrọwerọ yii, Onpetu tun mẹnuba ajọsepọ Yoruba ati awọn eeyan apa oke ọya, agbekalẹ ikọ Amotekun ati awọn ọna abayọ si eto aabo to mẹhẹ nilẹ yii.





