Fulani herdsmen: Oba Soun ló fí mi jẹ ọba Sabo ni Ogbomọṣọ- Alh Haruna Bala Abdulsala
Bi ọgọrun un ọdun sẹyin ni Baba baba wa jẹ ọba Sabo akọkọ ni Ogbomoso- Oba Sabo Haruna
Olorun ló di ìran Yorùbá, Hausa àti Igbo papọ̀- Oba Sabo ní Ogbomoso
BBC ṣabẹwo si Alahaji Haruna Bala Abdulsalami to n dari Sabo ni Ogbomoso nipinlẹ Oyo ni guusu Iwọ oorun Naijriia.
- Wo ohun tí Professor Peller wí tó kó bá a tí wọ́n fi rí i pa, ìyàwó rẹ̀, Lady Peller tú u síta
- Israel Adesanya fojú winá ẹ̀ṣẹ́ lọ́wọ́ Jan Blachowicz, ó fìdí rẹmi
- Èsì tí Daddy Freeze fọ̀ lórí owó N5m tí ilé ẹjọ́ ní kó san fún ọkọ obìnrin tó yàn l'álè rèé
- Kí nìdí tí gbajúgbajà òṣèré Sotayo Gaga ṣègbéyàwó bóńkẹ́lẹ́?

Oba Sabo yii sọ itan bi awọn baba nla rẹ ṣe de Ogbomọsọ ki wọn to jẹ Oba nibẹ.
O ṣalaye ipa pataki ti Oba Soun Ogbomoso ko ninu sisọ oun di ọba ni Sabo.
Oba Sabo ni Oba soun sọ pe ki oun maa dari gbogbo ẹya eeyan to ba ti n gbe ni Sabo ni Ogbomọṣo.

Bakan naa ni Oba Haruna Bala Abdulsalami sọ fun BBC Yoruba pe ewe lo n daabo bo ẹkọ ni ọrọ Hausa ati Yoruba.
O ṣakawe pe bi Yoruba ṣe pọ nilẹ Hausa ti wọn ko si fẹ wale mọ naa ni Hausa pọ nibi to ti ṣori rẹ.

Koda, O ni Yoruba ni iyawo oun gan an.
Oba Haruna Bala Abdulsalami ni ija Fulani, Hausa ati Yoruba ko jẹ tuntun rara.
- Ìjà ti parí, a ti gbà láti má a gbé ounjẹ wá sí ilẹ̀ Yoruba padà'- Hausa-Fulani Ọlọ́jà
- Ẹ wo bí ìyàwó Pasitọ Adeboye ṣe sàpèjúwe rẹ̀
- Ọlọrun má jẹ́ kí a jẹ́ gbèsè lókù báyìí tí a kò kó ọjá lọ sílẹ̀ Yorùbá mọ́- Hausa Oníṣòwò
- Nǹkan dé, Igboho ní káwọn ọ̀dọ́ ilẹ̀ Yorùbá lọ múra ògùn jọ nítorí ohun tó ń bọ̀ lọ́nà
- Àwọn ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ tó dá mi lọ́nà lọ́jọ́ Ẹtì fẹ́ pa mí ni -Sunday Igboho
Nitori pe o ti wa tipẹtipẹ.
O ni ẹya Fulani fẹ fi gbogbo ọna gbe ogo ẹya wọn ga ni.
- Ewú ńbẹ! tí ìjọba ìpínlẹ̀ bá sàkóso gbèndéke owó oṣù òṣìṣẹ́,wọ́n ò ní san N30,000, N10,000 ní wọ́n má á san -NLC
- Àwọn tó jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin gbé ní Zamfara fẹ́ yẹ̀yẹ́ Ìjọba Buhari ni- Hadi Sirika
- Wo ibi tí o ti lè fi orúkọ síìmù rẹ sílẹ̀ tàbí gba nọ́mbà tuntun tí síìmù rẹ bá sọnù
- Ẹ wo bí ìyàwó Pasitọ Adeboye ṣe sàpèjúwe rẹ̀



