June 12: M.K.O Abiola: Eyi ni àwọn ńkan tó yẹ kí ẹ mọ̀ nípa rẹ̀

Àkọlé fídíò, Abiọla ti jẹ́ olùdárí iwe ìròyìn Trumpeter rí ti Obasanjọ sì jẹ́ igbákejì rẹ̀

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Àkọlé fídíò, 'IBB da Abiola lẹ́yìn tó búra pẹ̀lú Quran'

Moshood Kashimaawo Olawale Abiola lo dije dupo aarẹ Naijiria lọdun 1993 labẹ ẹgbẹ oṣelu SDP.

Oun ati Alhaji Babagana Kingibe ni wọn jọ dije labẹ ẹgbẹ oselu SDP nigba naa.

Àkọlé fídíò, Ọdalẹ ni Babangida ati Abacha - Ọmọ Abiola

Ojọ kejila, oṣu kẹfa, ọdun 1993 ni wọn ṣeto idibo naa nibi ti ọpọ gba pe Abiola gbegba oroke ki ijọba Babangidea to wọgile e nigba naa.

Ojọ keje, oṣu keje, ọdun 1993 ni MKO Abiola jade laye nigba naa.