Shonekan's burial: Òní ní wọ́n yóò tẹ ara olóògbé Ernest Shonekan sí itẹ́ ni Ebony Vault ni Ikoyi ni ilu Eko

Shonekan

Oríṣun àwòrán, @Dapo Abiodun

Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 2

Ètò Ìsìnkú olóògbé Ernest Shonekan ti ń wáyé báyìí nile ijosin onigbagbo Cathedral Church of Christ, Marina ni ipinle Eko.

Skip Facebook post, 1

Content is not available

View content on FacebookBBC kò mọ̀ nípa àwọn ohun tí ó wà ní àwọn ojú òpó tí ó wà ní ìta.

End of Facebook post, 1

Loju Opo Facebook Gomina Dapo Abiodun to n tuko ipinle Ogun ni a wa yii to n safihan bi eto isinku naa se n lo

Skip Facebook post, 2

Content is not available

View content on FacebookBBC kò mọ̀ nípa àwọn ohun tí ó wà ní àwọn ojú òpó tí ó wà ní ìta.

End of Facebook post, 2

Skip Facebook post, 3

Content is not available

View content on FacebookBBC kò mọ̀ nípa àwọn ohun tí ó wà ní àwọn ojú òpó tí ó wà ní ìta.

End of Facebook post, 3

Shonekan

Oríṣun àwòrán, @Dapo Abiodun

Àkọlé àwòrán, Awon gbajugbaja oloselu to peju sibẹ

Die lara awọn aworan to jade nibi eto isin ale idagbere ti Onigbagbo fun oloogbe Shonekan ree:

Shonekan

Oríṣun àwòrán, @Dapo Abiodun

Àkọlé àwòrán, Gomina Dapo Abiodun lasiko to n sọrọ nipa ologbe
Shonekan

Oríṣun àwòrán, @Dapo Abiodun

Àkọlé àwòrán, Awon Ebi Oloogbe Shonekan

Kini o n ṣẹlẹ lonii?

Oni ọjọ kẹrin, oṣu keji, ọdun 2022 ni eto isinku Aarẹ Fidihe Naijiria nigba kan ri, Oloye Ernest Shonekan n waye.Ààrẹ fìdíhẹ Naijiria tẹ́lẹ̀, Ernest Shonekan ti jáde láyé

Ṣaaju ni won ti ṣeto isin idagbere fun oloogbe naa to dagbere faye lọjọ kọkanla, oṣu kinni , odun 2022.

Eni ọdun marunlelọgọrin ni Shonekan nigba ti o dagbere fun aye pe o digboṣe.

Ernest Shonekan

Oríṣun àwòrán, @Shonekan

Ta ni Shonekan?

Shonekan ni ọga agba ileeṣẹ United African Company of Nigeria Plc, UAC, ki ọgagun Ibrahim Babangida to yan gẹgẹ bii Aarẹ fidihẹ lọdun 1993.

Wọn bi Shonekan lọjọ kẹsan an, ọsu Karun un, ọdun 1936 niluu Eko.

O kawe ni ile ẹkọ CMS grammar school niluu Eko ati Igbobi College, ko to tẹsiwaju kẹkọgboye ni fasiti ilu London ati Harvard Business School.

Àkọlé fídíò, Bode George dá sí aawọ̀ Buhari, Obasanjo

Nibo ni Olopogbe naa dagbere si?

Iroyin ni pe Oloogbe Ernest Shonekan dagbere si ile iwosan Ever Care Hospital ni ipinle Eko.

Ojọ kẹtadinlogun, ọṣu kọkanla, ọdun 1993 ni Oloogbe Ogagun Sani abache gba ijọba Fidihe naa lọwọ Shonekan to n ṣe e lati ọjọ kẹrindinlọgbọn, oṣu kẹjọ, ọdun 1993

Àkọlé fídíò, Cancer: Àṣe ara mi ni iso ti n run gbogbo bí mo ṣe n ṣèrànwọ́ lórí jẹjẹrẹ

Bawo ni Isin Idagbere eto isinku naa ṣe waye?

Wọn ṣeto isin idagbere alẹ ikẹyin ati aisun onigbagbo fun Oloogbe Ernest Shonekan ni ale ana, ọjọ Bo, ọjọ kéta, ọsu keji, ọdun yii.

Skip Instagram post
Allow Instagram content?

This article contains content provided by Instagram. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read Instagram cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of Instagram post

Nibẹ naa ni awọn eekan bii awọn Gomina, awọn Aarẹ nigba kan ri, Aṣoju ṣofin, awọn biṣoọbu ati awọn eekan mii bii Senato Ibikunle Amosun ati aya re.

Loju opo Instagram goldmyne yii lo ti ṣafihan diẹ ninu eto naa ati bi ọmọkunrin oloogbe Shonekan ṣe n fi imoore han nibi eto naa lọwọ a\won to wa nibẹ.