Dr Frabz: Wọ ohun tí a mọ̀ nípa gbajúgbajù olórin ọmọ Naijiria, Dr Frabz tí wọ́n yìnbọn pa ?

@DoktaFrabz

Oríṣun àwòrán, Twitter

Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 2

Gbajugbaja olorin takasufe, Ayorinde Faboro ti gbogbo eniyan mọ si Dr. Frabz ti doloogbe.

Eyi ko ṣẹyin iroyin to n ja lori ayelujara wi pe wọn yinbọn pa a ni lorilẹ-ede Amẹrika nibi ti oun gbe.

Gẹgẹ bi iroyin ti gbajugbaja olorin, Nikki Laoye fi si oju opo Twitter, o ni niiṣe ni wọn yinbọn pa a.

Iroyin buruku leleyii o pe eniyan mi, Dr Frabz @DoktaFrabz, ti do loogbe... wọn yinbọn pa, talo ṣe eleyii? o dun mi gidigidi. iru iroyin wo leleyii?

Skip X post, 1
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 1

Skip X post, 2

End of X post, 2

Àkọlé fídíò, Badagry Historical Wells: Omi inú kànga Wawú ló ń kó ọpọlọ àwọn ẹrú lọ

Bakan naa ni akẹgbẹ rẹ olorin, Samklef ni '' erin nla lọ, ayo, a sọrọ ni sẹ meji ṣẹyin to n bere alaafia mi, mo wa si Maryland lana, mo si gbọ wi pe o ko si laye mọ... ọjọ ibanujẹ leleyii! o di gbere!RIP!

Lara awọn gbajugbaja olorin to ti fi ikẹdun wọn si ori ayelujara ni Davido, Samklef ati bẹẹ lọ.

Àkọlé fídíò, Femi Falana, Endsars: Awolowo kò fáààyè gba kí èèyàn máa yàgò fún Màálù nígboro

Tani Ayorinde Faboro, Dr Frabz @DoktaFrabz to doloogbe?

  • Ipinlẹ Ekiti ni wọn ti bi Ayorinde Faboro, Dr Frabz, amọ ilu Maryland, lorilẹede Amẹrika ni oun gbe ki o to di oloogbe ni ọdọmọde,
  • Ọdun mẹfa ni Ayorinde Faboro wa to ti bẹrẹ si ni kọ orin to si n ta duru,
  • Ọdun 2006 ni o bẹrẹ orin takasufe gẹgẹ bi i iṣẹ orin kikọ,
  • Inagijẹ orukọ rẹ, Dr. Frabz duro fun Doctor of Flavour, Rhythm and Blues,
  • Ayorinde Faboro ni oludasilẹ ileeṣẹ to n gbe orin jade, ti o pe orukọ rẹ ni N'sayne Entertainment,
  • Bakan naa ni o ti ṣe ọpọlọpọ iṣẹ pẹlu awọn gbajugbaja orin bii Naeto C, Davido, Dagrin, YQ, Shank, Omawumi ati bẹẹ bẹẹ lọ,
  • Lara awọn awo orin to gbe jade ni iwalaye rẹ ni orin Dagrin "Thank God", ati orin WizKid' "Bombay", ati "Joy".
Àkọlé fídíò, Mother tongue day 2021, Akomolede, YSAN: A ti parí iṣẹ́ lórí èdè ìperí Meta-Language Yorùb

Ẹ wo awọn ohun ti awọn gbajugbaja olorin n sọ nipa Ayorinde Faboro, Dr Frabz @DoktaFrabz

Skip X post, 3
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 3

Skip X post, 4

End of X post, 4

Skip X post, 5

End of X post, 5

Skip X post, 6

End of X post, 6

Àkọlé fídíò, Regent Ondo: Láti 1978 tí Bàbá mi ti jẹ Oba ni mo ti ms pé máà jẹ adelé- Magaret Omonije I
Skip X post, 7
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 7

Àkọlé fídíò, Coronavirus after one year in Nigeria: Níbo ni ọ̀rọ̀ Covid 19 dé dúró ní Nàìjíríà?