America immigration laws: Aàrẹ Joe Biden yóò so àwọn ẹbí ti ìjọba Trump túka papọ̀.

Oríṣun àwòrán, @Joe Biden
Ààrẹ Joe Biden yoou yóò so àwọn ẹbí ti ìjọba Trump túka papọ̀.
Ààrẹ Joe Biden ti gbe ìgbésẹ̀ àkọ́kọ́ láti yí àwọn òfin ti ìjọba ààrẹ Donald Trump gbé kalẹ̀ lórí àwọn àtìpó to wa sílẹ̀
Ó ṣe àgbékalẹ̀ ìgbìmọ̀ tí yóò ko ẹbí àwọn ti ìjọba Trump pín níyà pẹ̀lú òbí wọn láàrin ibodè U.S ati Mexico.
Lásìkò tí ó ń tọwọ́ bọ náà nílé ìjọba, Biden ni àwọn ṣetán láti ba gbogbo òfin tí kò tọ́ lásìkò ìjọba rẹ̀.
- Ààrẹ Joe Biden tí gba àwọn ọmọ Naijiria láàyé látí wá sàtìpó ní Amẹrika
- Gbogbo ojú la fi ń ṣọ́ Nàìjíríà báyìí lórí ọ̀rọ̀ ẹ̀sìn - ilẹ̀ Amẹ́ríkà
- Taa ni ọkùnrin 'tó tan mọ́ Naijiria' tó fún ọmọ Trump, Tiffany ní òrùka ìlérí ìgbéyàwó?
- Ìjọba Amẹrika yọ orúkọ Sudan kúrò nínú ìwé orílẹ̀-èdè tó ń ṣagbátẹrù ẹgbẹ́ agbésùnmọ̀mí
- Wo ohun mẹ́fà tí yòó ṣẹlẹ̀ níbi ìbúra ìjọba tuntun Biden àti Harris
- Wo ǹkan tó yẹ kí o mọ̀ nípa Joe Biden, aàrẹ tuntun ilẹ̀ America
Ní ọjọ́ ìṣẹ́gun, ni ilé ìgbìmọ̀ asòfin àgbà jan agbẹjọ́rò ọmọ bíbí Cuba kan Alejandro Mayorkas gẹ́gẹ́ bí akọ̀wé Homeland Secretary.
Ó jẹ́ àtìpó àkọ́kọ́ to ṣáájú àjọ ètò ààbò fún àwọn àtìpó àti àwọn to wa ni etí ibodè ìlú.
Ìbò tó gbé wọlé fihàn pé àárín ọmọ ilé igbimọ̀ asòfin àgbà ẹgbẹ́ òṣèlú Republican àti Democrat ko gún.
Biden ni òun yoo fi àwòrán obìnrin dúdú sórí owó dọ́là ilẹ̀ Amẹrika.
Ẹgbẹ̀gbẹ̀run àwọn òbí àti àwọn ọmọ tó ló ń gba ibodè Amẹrika wọlé lati Honduras, El Salvador àti Mexico lásìkò ogun ni wọ́n ti tì mọ́lẹ̀.
Lásìkò ìpolongo ìbò Trump lọ́dún 2016, ó gbájú mọ́ ọ̀rọ̀ ààbò lẹ́nu ibodè U.S.
Ó mú ìlérí rẹ̀ ṣe nípa kíkọ́ ọdi gíga láti pín Mexico, bí kò tilẹ̀ ṣe tó bí ó ṣe sọ, Mexico náà kò san owó ti wọn nínú àdéhùn náà.
- 'Ẹ yé bú Seyi Makinde, owó rẹ̀ ló fí ra Ọkọ bọ̀gìnì fún Alhaja Abosede Adedibu, Taye Currency, Mutiat Ladoja'
- Mọ̀ síi nípa Aung Suu Kyi tí wọ́n sọ sẹ́wọ̀n ní Myanmar àti bí ìgbàjọba ṣe wáyé níbẹ̀
- Ọlọ́pàá Ogun ké pe ẹni tó ni Pavillion Hotel láti wá ṣàlàyé ìdí tí kámẹ́rà fi wà nínú yàrá
- Ọ̀rọ̀ ìfẹ́ mú àgùnbánirọ̀ di èrò iléẹjọ́ ní ìpínlẹ̀ Kogi
- Ìròyìn ẹlẹ́jẹ̀ ní pé wọ́n pa ọmọ ogun mẹ́fà tó jẹ́ iran Igbo nikọ̀kọ̀ ní Abuja- Iléeṣẹ́ ológun





















