Stealing: Ilé-ẹjọ́ ní kí Danladi, awakọ̀ tó jalè gbálẹ̀ kóòtù f'ọ́jọ́ méjì

Oríṣun àwòrán, others
Ileẹjọ majisireeti ẹkun Wuse niluu Abuja ti pàṣẹ fun awakọ kan, Ahmed Danladi to jale pe ko gba ilẹ kootu fun ọjọ meji.
Awọn ọlọpaa lo fẹsun ole kan Danladi ẹni ọdun marunlelọgbọn.
Lẹyin ti Danladi gba pe oun jẹbi ẹsun ole ti wọn fi kan an, Adajọ majisireeti Omolola Akindele dajọ pe ki o wa gbale ileẹjọ lai si anfaani lati san owo itanran.
- Àìsí iṣẹ́ nígboro lọ̀pọ̀ ọ̀dọ́ fi fẹ́ gba iṣẹ́ Amotekun - Toogun
- A ti gba àwọn òṣìṣẹ́ 15,000 làti ṣètò ìdìbò gómìnà ní ìpínlẹ Ondo lóṣù kẹwàá - INEC
- Wo iye àwọn tó ti gbẹ̀mí ara wọn ní Nàìjíríà láàrin ọdún mẹ́rin ìjọba Buhari
- Gbèsè Nàìjíríà ti lé ní 18 tírílíọ́ọ́nù lábẹ́ ìṣèjọba Ààrẹ Buhari- DMO
- Wo ìyá ọlọ́mọ mẹ́ta tó ti pé ọdún 48 tó ń ṣe ìdánwò WAEC, kó le di nọ́ọ́sí
Ileeṣẹ ọlọpaa sọ pe ọkunrin kan Samuel Joseph lo mu ẹjọ Danladi wa lọjọ kinni, oṣu kẹsan an, ọdun 2020 yii.
Awọn ọlọpaa ṣalaye fún ileẹjọ pe ẹrọ ti wọn máa fi n fọ nnkan ọga rẹ ni Danladi jigbe ti o si fẹ ta fawọn to n sa ilẹ kiri ki aṣiri rẹ to tu
- Wo bí iṣẹ́ abẹ wákàtí mẹ́fà, tí wọ́n fi dóòlà ẹ̀mí ìjàpá tí ọkọ̀ tẹ̀, ṣe lọ
- Kò sóhun tó ń jẹ́ ‘Captivus’ nílẹ̀ Oodua, mágùn ni mágùn ńjẹ́ - Babaláwo
- Wo àwọn obìnrin abúlé kan tó dáwó ra ọkọ̀ láti máa gbé aláboyún lọ ilé ìwòsàn
- Ẹ fi dókítà àgùnbánirọ̀ rọ́pò àwọn dókítà tó ń yanṣẹ́ lódì - Ìjọba àpapọ̀ pàṣẹ
- Ìtàn rèé nípa bí Ogbomoso ṣe pa ọba, yọ nǹkan ọkùnrin rẹ jó kiri ìlú











