Yemi Farounbi: Yorùbá yóò dáàbò bo ara rẹ́, bí ìjọ́ba bá kùnà láti ràgà bò wọ́n
Aṣoju Naijiria tẹ́lẹ̀ lorileede Philipines, Ambassador Yemi Farounbi ti ni Sunday Igboho n ja fun ẹ̀tọ́ awọn eniyan rẹ ni lo se n jijagbara nitori naa ko ṣẹ si ofin.
Yemi Farounbi, lasiko to n ba BBC Yoruba sọ̀rọ̀ ni Igboho n tẹle ofin Naijiria to fun awọn eeyan laṣẹ lati da aabo bo ara wọn ni.
- Yemi Farounbi ní kí Sunday Igboho ṣe pẹ̀lẹ́
- Afurasí olóṣèlú tí ọlọ́pàá mú lórí ikú ọmọ mi, ló jẹ́ alátakò rẹ̀ nínú PDP - Baba Aborode
- Àìgbọ́ra ẹni yé ẹ̀yà Yoruba ló ń ṣe ìdíwọ́ fún òmìnira wa - Àkójọpọ̀ ẹgbẹ́ Yoruba l'àgbáyé
- Sunday Igboho ṣọ́ra ṣe, jẹ́ kí Seyi Makinde ṣiṣẹ́ tí òfin gbé le lọ́wọ́ - Ooni Ife
- 'Ǹkan tÍ Sunday Igboho Ṣe ní Ibarapa tún ti ṣelẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Ogun'
O fikun wi pe lati ọdun to ti pẹ ni Ilẹ Yoruba ti n pe fun atunto Naijiria, ki ẹya kọọkan ma a sakoso ara wọn, amọ awọn to n se ijọ́ba ko gba.
O tun woye pe ko si aar kankan tabi oloselu to le mu atunto ba Naijiria nitori ọ̀pọ̀ ohun to ti bajẹ́, awọ̀n igbesẹ́ to si gbọ̀dọ̀ gbe, bii lilọ̀ sile asofin ko le ran an lọ́wọ́.
Àwọn ìtàn mánigbàgbé tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Ìtàn ayé Henry Fajemirokun, olówó tó fi owó mọ Olúwa àti ènìyàn
- Ìtàn ayé Taiwo Oredein rèé, àgbà òṣèlú tó parí ayé rẹ̀ sọ́gbà ẹ̀wọ̀n
- Wo ìgbẹ̀yìn àwọn ọlọ̀tẹ̀ Yorùbá tó ran Fulani lọ́wọ́ láti kógun ja ìlú Osogbo
- Ìtàn ìgbé ayé Bode Thomas rèé, ó kọ́ wa láti máa kó ẹnu wa ní ìjánu
- Ṣo mọ̀ pé J.F Odunjo jẹ aṣòfin àti mínísítà nílẹ̀ yìí, yàtọ̀ sí pé ó jẹ́ òǹkọ̀wé?
- Ìtàn Àrọ̀gìdìgbà jẹ́ kí ń rò pé bàbá mi yan Yemọ̀ja ní àlè - Ọmọ Fagunwa
- Ó pé ọdún mẹ́rìnlélàádọ̀ta tí Akintola kú, ìdí abájọ ìja rẹ̀ pẹ̀lú Awolowo rè é
- Ìtàn Gbọnka àti Timi, akọni méjì tó borí Aláàfin Ṣango
- Wo ìṣẹ̀lẹ̀ márùn-ún tí kò bá pín Nàíjíríà sí yẹ́lẹ-yẹ̀lẹ
Nibayii. o wa rọ awọn Yoruba lati fi imọ sọkan nitori ibaṣepọ to dan mọran ni o le e mu ọjọ ọla to dara ba awọn ọmọ Yoruba.



