You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
NYSC Portal.ng: Ọjọ́ Kẹtà, oṣù yíì ní NYSC yóò ṣí ojú òpó fún àgùnbánirọ̀ Batch A, ẹ̀kúnrẹ̀rẹ́ wà ní ìbí...
Ajọ to n risi ọrọ awọn agunbanirọ lorilẹede Naijiria, NYSC ti fi ọjọ ti awọn agunbanirọ yoo bẹrẹ iforukọsilẹ fun awọn agunbanirọ ''Batch A'' ti ọdun yii silẹ.
Ajọ NYSC ni Ọjọ Kẹta, Oṣu Kẹta, ọdun 2021 ni awọn yoo si yóò ṣí oju ọpọ naa fun iforukọsilẹ lori ẹrọ ayelujara.
Ni oju ọpọ ikansiraẹni Twitter wọn ni wọn ti fi iroyin naa lede pẹlu alakalẹ ti awọn eniyan yoo tẹle lati fi orukọ silẹ.
- Francis Olusola Alao: Wọ́n ti ti ọ̀rọ̀ òṣèlú bọ ọ̀rọ̀ Sunday Igboho, ṣùgbọ́n....- Oba Olugbọn
- Ẹ tú ìgbéyàwó wa ká, níṣe n'ìyàwó mi máa ń gbá mi létí- ọkùnrin kan sọ fún iléẹjọ́
- Irọ́ ni o! A kò tíì rí àwọn akẹ́kọ̀ọ́bìnrin tó lé ní 300 tí wọ́n jí gbé ní GGSS Jangebe - Ìjọba Zamfara
- Èèyàn 240 míràn ló ṣẹ̀ṣẹ̀ tún lùgbàdì Covid-19 ní Nàìjíríà
- Sunday Igboho gbọdọ̀ gbàṣẹ ìdáàbòbò láti iléẹjọ́ tí kò ní jẹ́ kí ọlọ́páá mú un- Amòfin Ozekhome
Oju opo yii https://portal.nysc.org.ng/nysc1/ ni awọn eniyan ti le fi orukọsilẹ ti wọn ko ba tii fi orukọ silẹ tẹle.
Lẹyin naa ki o tẹ ẹka "Mobilization 2021 Batch A" fun oju opo tuntun fun awọn ti ko ba tii forukọsilẹ tẹlẹ.
Bakan naa ni wọn parọwa si awọn agunbanirọ ọun lati ma a wo oju opo ikansiraẹni wọn loore-koore.
Ti orukọ rẹ ba ni wahala tabi aṣikọ, o tun le e ṣe oun ti o tọ ni oju opo kan naa.
- Genevieve ṣàlàyé ànfààní tó wà nínú ìbásùn òwúrọ̀ kùtù fáwọn lọ́kọ láya
- A ò ní kó oúnjẹ lọ sílẹ̀ Yorùbá láì jẹ́ pé ààbò wà fáwọn Fulani níbẹ̀- Miyetti Allah
- Ọmọba Harry ṣọ kókó márùn ún nípa ìgbé ayé Amerika lẹyìn tóun àti Meghan fi London sílẹ̀
- Sunday Igboho gbọdọ̀ gbàṣẹ ìdáàbòbò láti iléẹjọ́ tí kò ní jẹ́ kí ọlọ́páá mú un- Amòfin Ozekhome
- Àwọn Olùkọ́ Yorùbá ní ìlú Ondo fọkọyọ lórí ètò Akọ́mọlédè àti Àṣà lórí BBC Yorùbá
- Wọ ohun tí a mọ̀ nípa gbajúgbajù olórin ọmọ Naijiria, Dr Frabz tí wọ́n yìnbọn pa ?
Ri daju wi pe sabuke rẹ ati ti ọjọ ibi rẹ wa ni ṣẹpẹ lai si abuku.