Power outage in Nigeria: Ìjọba àpapọ̀ ti gbé ìwé àlàyé jáde lórí àyípadà tí yóò bá iná ọba kó máa wá déédé

Ijọba àpapọ̀ orileede Naijiria ti ni oniruuru igbesẹ làwọn ti gbé lojuna àti mú agbende ba kí iná ọba padà bọ sípò èyí tó ti dẹnu kọlẹ láti bíi ọjọ melo kan jakejado Naijiria ti araalu sì ń pariwo ìnilára.
Laarin ọ̀sẹ̀ kan tó kọjá, ina ọba la iná to sì dojú b'olẹ̀ èyí tó sọ gbogbo ọmọ Naijiria sínú okunkun kò tún wà dá rìn, ó bọ si asiko ọ̀wọ́ngogo epo bentiroolu to n peléke sii lasiko kan náà.
Nínú atẹjade kan tí Minisita fún ọrọ iná ọba, Abubakar Aliyu fọwọ́ sí, ìjọba ni àwọn tí gbé ìgbésẹ alaseyori láti koju ipenija naa.
O ni gbogbo ẹ wa lati ibi tí wọn ti ń ṣakoso ìpèsè omi ni odo Kanji, Jebba àti ibi ìpèsè iná ọba ní Shiroro.
Ki lawọn igbesẹ naa to ti yoo muayipaa wa?
Gẹgẹ bi Minisita ṣe sọ ọ, àwọn ìgbésẹ pàtàkì tí wọn ti gbé rèé:
1. Ọ̀pá afẹ́fẹ́ gaasi ti àwọn èèyàn baje ti pada bọ sípò àti ibi ìpèsè iná ọba tó wa ni Okpai ti bẹ̀rẹ̀ isẹ padà to sì ń pín to ẹyẹ iná 300MW.
2. Ileeṣẹ tí wọn ń pè ní "The Nigerian Bulk Electricity" Plc ti gba àṣẹ láti kára bo idunadura pẹ̀lú àjọ NAOC lórí títa iná fún ní laarin ọjọ díẹ̀ pẹlu ìrètí láti dá ilé isẹ ìpèsè iná ni Okpai pada bo sípò kò sì já sókè sii tí yóò máa pèsè ẹyẹ iná 400MW.
3. Pé wọn yóò parí àtúnṣe lórí pípèsè afẹ́fẹ́ gaasi sì Ileeṣẹ iná ọba ní ọjọ́ Kọkànlá lógún oṣù Kẹta ọdún 2022 yìí kò lè máa pèsè ẹyẹ iná tó tọ́ 400MW.
- Wo àwọn àṣìṣe ikọ̀ ológun Russia ní Ukraine
- Ǹjẹ́ o ti gbọ́ nípa Da Rocha, olówó yalumọ àkọ́kọ́ nílẹ̀ Yorùbá
- Ife omi há sí ilé ìtọ̀ obìnrin kan fún ọdún mẹ́rin lẹ́yìn tó fẹ́ fi gba adùn ìbálòpọ̀
- Bí orísùn ìkùnsínú ṣe bẹ̀rẹ̀ láàrin Ebele Obiano àti Bianca Ojukwu rèé
- Wo ìlú tí wọ́n ti ń gbé òkú ọba wọn pọ̀n lórí ẹṣin lọ fún ìsìnkú nínú igbó
- Ológun ní kí aya mi bọ́ aṣọ kúrò lára, pa ọmọ mi mẹ́rin àtàwọn alátìlẹyìn mi - El Zakzaky
- Wo àwọn gómìnà ọgbọ̀n tó ti kó sí gbaga EFCC lórí ẹ̀sùn àjẹbánu àti àṣìlò ipò
- Sé lóòtọ́ọ́ ní ọlọ́pàá yìnbọn mọ́ àgùnbánirọ̀ n'Ibadan?
- Àìsàn tó ń ṣe ọ ní ohun ṣe pẹlú oorun rẹ - Onímọ
4. Láti leè ṣe àmúlò iná ọba tí Ileeṣẹ iná ọba tí Niger Delta àjọ to n mojuto ọ̀rọ̀ iná ọba tí fọwọ́ sì ìpèsè gaasi ara ọ̀tọ̀ lati Ileeṣẹ to n ṣe kárakára gaasi fún àwọn iṣẹ́ pajawiri kí ohun náà lè bẹ̀rẹ̀ si jí pèsè ẹyẹ iná bíi 800MW.
5. Fún ṣáá díẹ̀, ó ní àwọn tí ni adehun pẹlu àjò kan tó wà lábẹ́ Ileeṣẹ NNPV lórí Ileeṣẹ to n pese afẹ́fẹ́ gaasi ni Okoloma óò lè padà bo sípò kò máa pèsè 650MW.
6. Pelu bí idenukole to waye yóò ṣe dùn èèyàn tó, ìjọba ni ó jé ọgbọ́n àmúlò láti bójú tó ìpèsè iná 330KV.
Gbogbo igbese tí wọn lawọn ń gbé yìí ni lati mú erongba Ààrẹ ṣẹ fún iná ọba.














