Egbejila Fish Village: Ọlọ́sìn ẹja ní àìríṣẹ́ṣe ló mú káwọn sin ẹja àmọ́ ijọba Kwara ko jẹ káwọn rimu mi.
Isẹ agbẹ ni isẹ ilẹ wa, ẹni ti ko ba sisẹ, yoo jale
Eyi lo mu ki awọn ọdọ kan nilu Ilorin se fi isẹ banki silẹ, maa dawọle isẹ ọsin ẹja, lsna ati mu agbega ba isẹ naa.
Nigba ti wọn n ba BBC Yoruba sọrọ, awọn ọdọ naa ti wọn da abule ọsin ẹja silẹ ni agbegbe Egbejila, ni eti bebe odo Asa nilu Ilorin salaye pe ohun to mu wọn dawọle isẹ naa.
Àwọn ìtàn mánigbàgbé tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Duro Ladipọ, ìlúmọ̀ọ́ká òṣèré tíátà àti ọmọ àlúfà tí kò gbàgbé àṣà ìbílẹ̀
- Ìtàn ìgbésí ayé Oshodi, ọmọ Tápà léǹpe tó di akọni ní ìlú Eko
- Ìtàn Manigbagbe: Àwọn àjakalẹ-àrun to ti wáyé rí ṣáájú Coronavirus
- Wo àwọn gbajúmọ̀ òṣèré Yorùbá tí kìí ṣe ọmọ káàárọ̀ oòjíire
- Ǹjẹ́ o mọ àwọn òṣèré bí Oyin Adejọbi, Funmi Martins àtàwọn míì tó ti dágbére fáyé?
Bakan naa ni wọn salaye ipenija to wa niwaju wọn, paapaa bi ijọba Kwara se ni ki wọn ko ọsin ẹja wọn kuro lagbegbe naa nitori ọsin ẹja naa n ba omi Asa jẹ.
BBC Yoruba tun ba ijọba Kwara naa sọrọ lori ohun to ri lọbẹ, to fi wa iru sọwọ lati le awọn ọlọsin ẹja ọhun kuro ni abule ti wọn wa.
- Ìtàn ìgbé ayé Isola Ogunsola 'I-sho Pepper', ògbóǹtagí òṣèré tíátà tó s'eré Yorùbá yíká Nàìjíríà
- Kí ló wà ní ìdí igbá tí àwọn olorì Aláàfin máa ń tí lóde Ọ̀yọ̀
- Ìjà Awolowo, Akintola àti ogun 'Wẹtiẹ', ẹ̀kọ́ wo ló kọ́ wa?
- Igbo Olodumare rèé, níbi tí Ìgbín ti tóbi ju Ìjàpá lọ
- Ìdílé márùn-ún tó gbajúmọ̀ fún òwò ẹrú nílẹ̀ Yorùbá
- Wo ìtàn ayé gbajúmọ̀ adigunjalè méje nílẹ̀ Yorùbá
- Jimoh Odutola, akọni oníṣòwò tí kò kàwé, àmọ́ táwọn Ààrẹ orílẹ̀-èdè ń ké sí láti wá dá iléesẹ́
Abọ iwadii wa ree nipa bi abule ọsin ẹja ni Asa se gbooro si, awọn anfaani to wa nidi isẹ naa ati ipenija to n ba wọn finra.





