Oba Oloyede Akinghare youngest king: Oba Oloyede ti pari ìwé mẹ́wàá báyìí,ó sọ ohun tí àwọn Olùkọ ṣe fun un nilé ẹ̀kọ́
Lati ẹnu ọna afin ni ipele ipele ati isọri isọri awọn eeyan agbaye ti n ko okiki Ọba tuntun to gori itẹ gẹ́gẹ́ bi ọdọ.
Ọba Oloyede Akinghare lo gba ade gẹgẹ bi ọba to kere julọ nilẹ Yoruba.
BBC Yoruba lọ ṣe Kaabiyesi rẹ ni aafin Ọba Oloyede nilu Okelusẹ gẹgẹ bi Ọbalayé tó kéré jùlọ nílẹ̀ Yorùbá, Oloyede Akinghare tó gbadé .

- Lọ́jọ́ tí wọ́n fẹ́ bí Damilare abúrò Mide, ǹkan fẹ́ wọ́lẹ̀, kò sí bàbá nílé àmọ́ ... - "Uncle" Damilare Funmi Martins
- Ta ni gbajúgbajà òṣèré Funmi Martins ìyá Mide-Martins àti kí ló ṣekú pa á lẹ́ni ọdún 38?
- E má ṣìwágbọ́, Orí ayélujára ní èsì ìdìbò yóò ti máa jáde ní 2023– INEC
- Wo obìrin méjì tó ń fi ìbásùn inú yìyín "Snow" ṣara rindin kí ọlọpàá tó ká wọn
- Wo bí wọ́n ṣe dé adé fún Oba Zulu tuntun ni South Africa..
- Iléẹjọ́ tó ń gbọ́ awuyewuye ètò ìdìbò ti fún Gómìnà Oyetola láṣẹ láti ṣàyẹ̀wò àwọn ohun eèlò ìdìbò Osun
Lootọ, o ṣeeṣe ki iru eyi ti waye ri lawọn ẹya orilẹede Naijiria mii ṣugbọn ko wọpọ, nilẹ Yoruba, ipinlẹ Ondo ni Ọba to kere julọ ti kọkọ ṣẹ wa.
Oloyede Akinghare gun ori itẹ gẹgẹ bii Kabiyesi Arujale Ojima ti ilu Okelusẹ ni ijọba ibilẹ Ọsẹ, ni ipinlẹ Ondo.
Lẹyin ọdun mẹta ti baba rẹ waja lo gori itẹ.

Oríṣun àwòrán, Yetunde Olugbenga
To fi mọ awọn ọmọ ileẹ̀kọ́ rẹ lo wa tilu tifọn ti wọn n yẹ ọba wọn si.
Gẹgẹ bi ọkan lara oun ti a mubọ, Ọba Oloyede ṣi wa lẹnu ẹkọ rẹ, o ni ipo ti oun wa ko fa idiwọ kankan fun ẹkọ oun.

Oríṣun àwòrán, Oba Oloyede Akinghare
- Mó padánù ipò gómìnà nítorí ẹgbẹ́ òṣèlú márùn-ún parapọ̀ làti kojú APC lọ́dún 2019 ni ṣùgbọ́n....- Adelabu••
- Bí ẹranko igbó ṣe bu ìdí obìnrin kan tó ń bẹ̀rẹ̀ yàgbẹ́ jẹ
- Àwọn Dókìtà bẹ̀rẹ̀ ìyanṣẹ́lódì ní FMC Owo, Ondo
- Ìyàwó wọ sòkòtò fún ayẹyẹ ìgbéyéwò rẹ̀, ní wáhálà bá bẹ́ sílẹ̀
- Àwọn olóṣèlú gbọdọ̀ máa fi Ògún búra, bí Nàìjíríà bá fẹ́ dẹ́kun ìwà àjẹbánu - Guru Maharaj ji
- Shina Peters dúpẹ́ lọ́wọ́ àwọn abiyamọ ayé lórí ọ̀rọ̀ ọmọ tí Funmi Martins bí kó tó papòdà
"Ọlọrun maa ran wa lọwọ, nkan ti mo ba ti sọ naa ni ilu maa tẹle ti wọn maa gba bẹẹ́".
Ẹwẹ, Kabiyesi Akinghare ni ko tii si ọrọ fifẹ iyawo lọrọ oun o!

