Zulu king: Idálu ni ìṣèlú: Wo bí wọ́n ṣe dé adé fún Misuzulu ka Zwelithini gẹ́gẹ́ bí Oba Zulu tuntun ni South Africa..

Fun oju lounje ayọ pelu aworan bi wọn se de ade fun Oba Zulu tuntun ni orilẹ-ede South Africa.

Won de ade fun Oba Zulu tuntun

Oríṣun àwòrán, AFP

Àkọlé àwòrán, Opọlọpọ ero lo tu sita l;asiko ti wọn n de ade fun Misuzulu ka Zwelithini gẹgẹ bii Oba Zulu tuntun ni South Africa.
Won de ade fun Oba Zulu tuntun

Oríṣun àwòrán, AFP

Àkọlé àwòrán, Lọ́jo Abameta to kọja ni Oba Misuzulu gba ade lati maa tuko awon eeyan Zulu lọ bayii
Won de ade fun Oba Zulu tuntun

Oríṣun àwòrán, AFP

Àkọlé àwòrán, Ni kete ti won de ade Zulu fun un lo jade lati ipebi ninu aṣọ to kun fun iyẹ dudu to si mu ọ̀kọ̀ nla kan dani pẹlu ìdi rẹ̀
Won de ade fun Oba Zulu tuntun

Oríṣun àwòrán, AFP

Àkọlé àwòrán, Eni ọdun mejidinlaadọta ni Miuzulu tuntun ti wọn yan sipo pẹlu ariwo ayọ nla. O si seleri lati mu irẹpọ pada si ẹkun Zulu.
Won de ade fun Oba Zulu tuntun

Oríṣun àwòrán, AFP

Àkọlé àwòrán, Aafin KwaKhangelamankengane ni agbegbe ẹkun KwaZulu-Natal ni wọn ti de ade fun Oba tuntun naa.
Won de ade fun Oba Zulu tuntun

Oríṣun àwòrán, EPA

Àkọlé àwòrán, Awọn Omidan Zulu naa yọ ayọ nla lori ade tuntun ti Oba naa gba nibẹ
Won de ade fun Oba Zulu tuntun

Oríṣun àwòrán, AFP

Àkọlé àwòrán, Awọn akọni ẹkun Zulu naa dabira pẹlu ijo ati ayọ nibẹ.
Won de ade fun Oba Zulu tuntun

Oríṣun àwòrán, AFP

Àkọlé àwòrán, Ite Oba Zulu yii ko ni ipo kankan ninu eto iṣelu South Africa sugbon ekun naawa lara ekun to ni ero to pọju lọ ni eyi to n fun Oba ibẹ lagbara lasiko idibo.
Won de ade fun Oba Zulu tuntun

Oríṣun àwòrán, AFP

Àkọlé àwòrán, Wọn ṣeto ayẹyẹ naa lain nii fi se pe awọn kan n kun pe oun kó ni ade naa tọ si. Eyi ko ṣeyin pe awọn ibatan obinrin Oba kan sọrọ nipa iwe akọsilẹ Baba wọn ko to ku.