Ọmọ Jerry Rawlings ké gbàjarè pé àwọn gbájúẹ̀ fẹ́ forúkọ bàbá rẹ̀ gbowó ìsìnkú

Oríṣun àwòrán, ZANETOR AGYEMAN-RAWLINGS/TWITTER
Ọmọbinrin to dagbaju laarin ọmọ aarẹ orile-ede Ghana to papoda laipẹ ti figbe ta pe awọn gbajuẹ́ n fi orukọ baba oun gbowo isinku loju opo ayelujara.
Zanetor Rawlings fi ọrọ yi sita ninu atẹjade loju opo Facebook rẹ lọjọbọ wi pe awọn opo ayederu ni wọn lo lati gba owo yi jọ.
O ni niṣe ni wọn n sọ awọn to ba ti ba oun kẹdun ti wọn si n ranṣẹ si wọn lati mu owo isinku baba rẹ wa.
- Ta ni olóògbé Jerry Rawlings, tí wọ́n fún ní àlàjẹ́ 'Junior Jesus '
- Ilé ẹjọ́ tú ìgbéyàwó ọdún mọ́kànlá ká nítórí pé ìyàwó fí ìbálòpọ̀ dun ọkọ rẹ̀
- Ṣe lóòtọ́ ni ejò ń pọ owó fún Ginimbi, ọ̀dọ́mọdé olówó kó tó jáde láyé?
- Ìbálòpọ̀ ọ̀lọ́jọ́ méje mú kí ilé ẹjọ́ tú ìgbéyàwó ọdún mẹ́wàá ká ní Ibadan
- Kí lo mọ̀ nípa ìbẹta kan ṣoṣo tí Alaafin Oyo bí? Wọ́n pé ọdún méjìlá báyìí
Aṣoju ile aṣofin Ghana to n ṣoju ẹkun idibo Klottey Korle ni Zanetor n ṣe.
Lọjọ kejila, oṣu Kọkanla ni Jerry John Rawlings aarẹ Ghana fi aye silẹ lẹni ọdun mẹtalelaadọta.
- Àjọ Hisbah tó jẹ́ ọlọ́pàá Sharia ní Kano kọ lẹ́tà ìkìlọ̀ lórí lílo èdè 'Black Friday'
- Ìgbín, iṣu, epo, àádùn, obì, iyọ àti oyin wa lára ohun ti a fi sọ ọmọ Ọọni lórúkọ!
- Àpò òfìfo ni a bá nígbà tí a gbàjọba lọ́dún 2015, ṣùgbọ́n a ti ṣiṣẹ́ ribiribi - Ìjọba àpapọ̀
- Fatai Rolling Dollar, Ọmọ ìdílé oyè tó gbé igbá orin tí Ebenezer Obey ń ṣiṣẹ́ lábẹ́ rẹ̀!
- Orúkọ Aisha Yesufu náà wọ inú BBC 100 Women tí a fi ń sọri àwọn obìnrin tó pegedé ní 2020
Ijọba aarẹ Nana Akufo-Ado ti ṣaaju kede ọjọ meje idarọ lorile-ede Ghana gẹgẹ bi wọn ṣe n palẹmọ isinku ti ijọba fẹ se fun.









