Davido: Kí ló fa ariwo lórí ìdọ́rẹ́ òun àti Chioma aya rẹ̀ lójú òpó Instagram?

Oríṣun àwòrán, davido/twitter
Ariwo ta ni owurọ ọjọ Abamẹta lori ayelujara nigba ti awọn eeyan bẹrẹ si ni gba a bi ẹni n gba igba ọti pe gbajugbaja akọrin takasufe, Davido ati iyawo rẹ ti kẹyin sira wọn lori ikanni Instagram.
Iroyin naa ṣalaye wi pe awọn mejeeji ti wọgi le orukọ arawọn loju opo ẹnikeji wọn.
- 'A kẹ̀yìn sí Ivory Coast, owó yín ò lè máa jẹ́ "eco" táa ti mú fún àjọná owó ECOWAS'
- Ẹgbẹ́ kan fún Tinubu ní wákàtí mẹ́rìnlélógún láti sọ èrò rẹ lórí Amọtẹkun
- 'Ẹ yé pè wá ní NEPA mọ́ tí ẹ bá fẹ́ ká fún yín ní iná, DisCos ni wá'
- Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ afurasí tó ní òun ló jí ọmọ gbé láti parọ́ mọ́ pásítọ̀ ìjọ Sotitobire
Ohun ti iroyin loju opo ayelujara atawọn ileeṣẹ iroyin abẹle n sọ ni pe, igbesẹ naa waye lẹyin ti Ọga ileeṣẹ agborinjade Golden Boys Record, King Patrick ke gbajare sita pe ibi a foju si ọna o gba bẹ ati pe arakunrin Peruzzi ti ọpọ n wo gẹgẹ bii ẹgbọn Chioma, iyawo Davido kii ṣe ẹgbọn rẹ, ọrẹ ikọkọ rẹ ni.
Nibayii lẹnu wakati melo lọjọ kan naa, Davido ati aya rẹ Chioma tun ti bẹrẹ si ni tẹle ara wọn gẹgẹ bii ọrẹ lori oju opo ayelujara awọn mejeeji.
Amọṣa nigba ti ọrọ yii n ja ranyinranyin, oniruuru ọrọ ni awọn ololufẹ awọn lọkọlaya yii atawọn ọmọ Naijiria kan sọ. Diẹ lara rẹ niwọnyii.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 1

End of X post, 2

End of X post, 3

End of X post, 4

End of X post, 5

End of X post, 6