Blackout: Ẹ wo ohun tí àwọn ọmọ Nàìjíríà ń sọ lẹ́yìn ìyanṣẹ́lódì ilẹeṣẹ́ mọ̀nàmọ́ná

Ohun elo apinnaka

Oríṣun àwòrán, Twitter/RoryPetzer

Àkọlé àwòrán, Ẹnikan ni ileeṣẹ mọnamọna lo n ṣokunfa bi awọn ọdọbirin ṣe n gboyun ojiji
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 3

Ni kete ti ẹgbẹ oṣiṣẹ ileeṣẹ mọnamọna Naijiria gunle iyanṣẹlodi ni ọpọ ọmọ Naijiria ti bẹrẹ si n fi eroungba wọn lede lori ipinu ọhun.

Bo tilẹ jẹ pe ẹgbẹ naa ti dawọ iyanṣẹlodi ọhun duro fun igba diẹ, awọn ọmọ Naijiria ko dawọ ọrọ ti wọn sọ duro.

Bi awọn kan ṣe n bu ẹnu atẹ lu ileeṣẹ amunawa, ni awọn mii n sọ pe ko kan wọn, bẹẹ ni awọn miran n fi epe ransẹ si ileeṣẹ ọhun.

Esi lori ina mọnamọna

Awọn kan tilẹ sọ pe ko si iyatọ laarin igba ti wọn gunle iyansẹlodi ati igba ti wọn n ṣeṣẹ.

@Official_imo ni ileeṣẹ mọnamọna lo n ṣokunfa bi awọn ọdọbirin ṣe n gboyun, latari bi wọn ṣe n gba ina sara ẹrọ ibanisọrọ wọn nile okunrin.

Skip X post, 1
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 1

Black Abraham Lincoln ni tirẹ sọ pe oun ti fun ara oun ni isinmi lẹnu iṣẹ titi di igba ti ijọba yoo wa ojutu si ọrọ ina ọhun.

Skip X post, 2
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 2

Oxlade Junior bu ẹnu ẹtẹ lu ijọba apappọ latari bi ko ṣe le pese ina gẹgẹ bi ileri to ṣe ṣaaju idibo.

Skip X post, 3
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 3

Esi lori ina mọnamọna
Àkọlé fídíò, Silas Robotic Engineer: Kò sí ǹkan rere tí ọmọ Nàìjíríà kò lè ṣe

Ẹ wo awọn ohun miran ti awọn ọmọ Naijiria n sọ.

Skip X post, 4
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 4

Skip X post, 5

End of X post, 5

Skip X post, 6

End of X post, 6

Skip X post, 7

End of X post, 7

Skip X post, 8

End of X post, 8

Esi lori ina mọnamọna

Ki lo ti ṣẹlẹ sẹyin?

A ó gùnlé ìyanṣẹ́lódì lọ́dún tuntun tí ìjọba bá kọtí ikún síwa - Ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ ilẹeṣẹ́ mọ̀nàmọ́ná

Oṣiṣẹ ileeṣẹ mọnamọna

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Ṣaaju ni kutukutu owurọ oni ni ẹgbẹ ọhun dawọ iyanṣelodi ti wọn gunle tẹlẹ duro fun saa diẹ

Ẹgbẹ awọn oṣiṣẹ ileeṣẹ apinnaka lorilẹ-ede yii NUEE , ti sọ pe oun yoo gunle iyanṣẹlodi miiran ti ijọba ko ba ṣe ohun ti wọn n fẹ.

Akowe apappọ fun ẹgbẹ naa, Joe Ajaero sọ fun BBC pe, idi iyanṣẹlodi ọhun ko ṣẹyin bi ijọba ṣe kọ lati mu adehun to wa laarin rẹ ati ẹgbẹ naa ṣẹ.

Ati pe bi ijọba ṣe n yọ owo ifẹyinti awọn oṣiṣẹ ọhun, to si kọ lati fi owo naa si apo to yẹ ko wa, ati awọn idi miran.

Àkọlé fídíò, Akure Kidnap: Àwọn abiyamọ fẹ̀hónúhàn lórí ọmọ tí wan jígbé nílé ìjọsìn Akurẹ

Ṣaaju ni kutukutu owurọ oni, ọjọbọ ni ẹgbẹ ọhun dawọ iyanṣelodi ti wọn gun le tẹlẹ duro fun saa diẹ.

O ni wọn da iyaṣẹlodi ọhun duro di oṣu kini, ọdun 2020.

Joe ṣalaye pe o ṣeeṣe ki ẹgbẹ NUEE gunle iyanṣẹlodi miiran lọdun 2020 ti ijọba ko ba ṣe ohun ti wọn n fẹ.

O ni ẹgbẹ NUEE ko bere ohun miran lọwọ ijọba, bikoṣe pe ki ijọba mu adehun to wa laarin wọn tẹlẹ ṣẹ.

Ni kete ti ẹgbẹ naa ti fi ọrọ lede pe oun yoo gunle iyanṣẹlodi ni ọpọ agbegbe lorilẹ-ede yii fara kaasa okunkun birimu.

Àkọlé fídíò, Àrà méèrírí lórí òkè táwọn ará ìlú Idanre l'Ondo ń gbé láyé gbọ́ngan sẹ́yìn