FUTA: Àwọn mẹ́jọ ló ṣíná ìyà fún Bolu ní FUTA
Wọn da ọgbọn tàn mi wa sinu iyara wa fiya jẹ mi- Boluwatifẹ
Laipẹ ni fidio kan lu ori ayelujara pa pe awọn akẹkọọ ile iwe giga ti ijoba apapọ ni akurẹ ni ipinlẹ Ondo, iyẹn Federal University of Technology lu akẹgbẹ wọn kan FUTA pàṣẹ lọ rọọ́kún nílé f'ákẹ́ẹ̀kọ́ méje tó lu akẹgbẹ́ wọ́n.
Lẹyin ti fidio naa ti wọn ti da seria iya fun Boluwatife Esther Adekunle jade ni alaṣẹ fasiti naa ti ni ki wọn lọ rọọ kun nile Akẹ́kọ̀ọ́ mẹ́fà tó lu akẹẹgbẹ́ wọn ní fásitì FUTA dèrò ilé
Adekunle Esther Boluwatife, ti ọrọ kan ba BBC Yoruba sọrọ lori ohun to ṣẹlẹ gangan ni Akurẹ .
O ṣalye ajọṣepọ to wa laarin oun ati Faith ti wọn kọkọ jọ gbe ati Obalọla ati Funmi to ni iyara ti wọn ti na an laiyọ Jessicca naa silẹ.
Imoran iya Bolu ṣe pataki si awọn ọdọ iwoyi pe ki wọn ṣọra fun aṣa kiko ọrẹ oriṣiiriṣii jọ laini idi gidi.
Yoruba ni fi ọrẹ rẹ han mi; maa sọ iru eeyan ti o jẹ ati pe ki gbogbo akẹkọọ maa ranti iru ọmọ ẹni ti awọn n ṣe.