Ibadan new born kidnap: Monsurat Lateef ṣàlàyé fún BBC bí obinrin kan ṣe jí ọmọ rẹ̀ gbé àti ibi tí ọ̀rọ̀ dé dúró
Omo Naijiria e dakun ẹ gab mi ni ariwo ti Iya Ikoko n pa bayii ni Itamerin ni Ibadan.
Ọmọ Nàìjíríà, ẹ dákun, ẹ bá mi wá ọmọ mí- Monsurat Lateef
Leyin ti iroyin gba igboro kan pe obinrin kan ji ikoko Monsurat Lateef gbe ni Abe Koko ni BBC Yoruba ti de sibe lati mọ ohun to ṣẹlẹ gangan.Ọwọ́ ti tẹ obìnrin kan lórí ẹ̀sùn ọmọ tuntun tó dàwátì ní Ibadan- Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá
- Wo bí Ife ṣe pa ara rẹ̀ lẹ́yìn tó dáná sún Bolu ọkọ rẹ̀ torí pé ó ká 'chat' pé obìnrin míì lóyún fún ún
- Àjọ Yuroopu fẹ́ kọ afẹ́fẹ́ gáàsì Russia láti fi ti Nàìjíríà dípò rẹ̀
- Kí ló ṣẹlẹ̀ tí ìró ìbọn tún fi ń dún lákọlákọ nílùú Owo nípinlẹ̀ Ondo-
- Ọkùnrin kan jóná mọ́ inú ọkọ̀ ní Kwara
- Ojú gbàmí tì fún un yín, ẹ̀yin asòfin Nàìjíríà tí ẹ ń wo ọ̀rọ̀ Nàìjíríà níran–Aliyu Wabara
- Ademola Adeleke yan ìgbìmọ̀ tí yóò mójútó bí agbára yóò ṣe pàárọ̀ ọwọ́ ní Osun
Monsurat Lateef ati ọkọ rẹ to jẹ Baba ikoko naa salaye ni kikun nibi ti wọn ti pade obinrin naa ati bo ṣe wa Monsurat wa sile lọjọ keji leyin ti wọn pade.
Nile iwosan to ti lo gab abẹrẹ ajẹsara fun ikoko ni ọrọ yii ti bẹrẹ.
Bẹẹ, ikoko to dawati yii ni omọ akọkọ ti o ṣẹṣẹ duro lọwọ Monsurat lẹyin ikunlẹ mẹta.
Monsurat ni pe bii 'Remote' ni obinrin naa fi n tẹ oun lati igba ti wọn ti pade.
Koda, aṣọ Monsurat ni obinrin naa wọ gbe ọmọ salo ti o si bọ aṣọ ara rẹ silẹ.
- Fayose dèrò ilé ìwòsàn, ó ṣiṣẹ́ abẹ méjì láàrín oṣu márùn ún
- Ọba méje wàjà láàrin oṣù mẹ́sàn án l‘Oyo, ominú ń kọ mí- Gani Adams
- Wo ìdí táwon agbébọn fi tú mẹ́ta nínú arinrinàjò reluwé Abuja sí Kaduna sílẹ̀
- Nkan tó yẹ kí o mọ̀ nípa Daniel Okoh, Ààrẹ tuntun tí CAN yàn fi rọ́pò Supo Ayokunle -
- Ààrẹ Buhari, Sanwo-Olu, Dapo Abiodun ki Amusan to gba ‘’World 100m Hudles Champion”
Ileeṣẹ ọlọpaa ni ipinlẹ Oyo sọ pe ọwọ ti tẹ obinrin afurasi kan bayii ti iwadii si ti bẹrẹ lori rẹ ni ipinlẹ Oyo.