Ekiti 2022: Iṣẹ́ tí ìjọba ṣe sílẹ̀ ní a máa tẹ̀síwájú lórí ẹ torí mo ní ìrírí tó pọ̀ ni Ekiti- Biodun Oyebanji
Ipò òṣèlú tó kére jù ni mo ti bẹ̀rẹ̀ ní ekiti, mo mọ ohun tó kàn- Biodun Oyebanji
Biodun Abayomi Oyebanji to n dije dupo gomina Ekiti gbalejo BBC Yoruba.
O salaye ohun to pinnu lati se fun awọn oludibo ti wọn ba yan oun.
Ipo oṣelu to kere julọ ni ipinlẹ Ekiti lo ni oun ti bẹrẹ iṣẹ to si ti wa ni iriri to pọ bayii.
- Ǹjẹ́ o mó Oladosu, ọmọ Peter Fatomilola tó jẹ́ olùdíje ẹgbẹ́ òṣèlú NNPP-
- Nkan tó yẹ kí o mọ̀ nípa Olaniyi Ben Agboola, olúdíje ẹgbẹ́ PRP nínú ìdìbò gómìnà ipinlẹ Ekiti
- Olóṣèlú ni mí, mo mọ ìṣòro àwọn ará Ekiti- Bisi Kolawole PDP
- Ajagunigbala Moses Olajide, pásítọ̀ tó fẹ́ di gómìnà ipinlẹ Ekiti lábẹ́ àsìá ẹgbẹ́ AAC
- Ayé àwọn èèyàn Ekiti dára nígbà tí wọ́n wà lábẹ́ Ondo ju ìsìnyí lọ- Reuben Famuyibo Accord
- Ìtẹ̀síwájú àwọn eèyàn Ekiti ló jẹ́ mi lógún- Kemi Elebute Halle
- Ikọlù,APC, SDP Ekiti 2022- Èèyàn kàn kú,ẹgbẹ́ méjèèjì tako ará wọn
- Ojú ará oko, ojú ará òkè ni wọ́n fi ń wo àwa ará Ekiti, mo fẹ́ tún Ekiti ṣe ni- Debo Ranti Ajayi
- Ọlọ́run fẹ́ gbé Ekiti gorí ẹṣin ló ṣe ní kí ń díje gómìnà nínú ẹ́gbẹ́ ẹlẹ́ṣin - Segun Oni
- Adájọ́ da ẹjọ́ Ilana Omo Oodua nu, tó ní kí wọn wọ́gilé ìbò gómìnà Ekiti àti Osun
Ki tun ni Biodun Oyebanji tun sọ?
Oludije labẹ ẹgbẹ APC to n dari ipinle Ekiti lọwọlọwọ yii tun mẹnuba erongab rẹ fun ọrọ aje ati eto aabo ipinle Ekiti.
O ni ko si oludije to ti sise sin Ekiti bii ti oun fun ọpọlọpọ ọdun bayii.