Kemi Elebute Halle ṣàlàyé ohun tó fa ìjínígbé ni ìpínlẹ̀ Ekiti àti ọ̀nà àbáyọ

Àkọlé fídíò, Kemi Elebute Halle ṣàlàyé ohun tó fa ìjínígbé ni ìpínlẹ̀ Ekiti àti ọ̀nà àbáyọ

Ẹ̀yin Obinrin Ekiti, ẹ je ki a dan obinrin wo nitori awọn ọkunrin ti kuna ninu iṣejọba Ekiti- Elebute Halle

Erelu Kemi Elebute- Haale ni obinrin akọkọ to gbe igba idibo lati dije dupo gomine ni ipinle Ekiti.

Abe asia ẹgbe oselu Action Democratic Party ADP ni ipinle Ekiti lo ti n dije.

O menuba die lara awọn iṣẹ to ti gbe ṣe fun awon eniyan ipinle Ekiti saaju asiko idibo yii.

Kini Elebute Halle tun so?

Erelu Kemi elebute Halle salaye pataki iwe kiko ati ise agbẹ ni ipinlẹ Ekiti.

O ni idi niyii ti wọn fi pe ipinle ni Fountain of knowledge to jẹ orisun imọ Naijiria.

O sọ nipa kudiẹ kudie to wa ni Ekiti ati ọna abayọ si awọn isoro naa.

Ojọ Satide, ọjọ kejidinlogun oṣu yii ni eto idibo lati ayn gomina tuntun yoo waye ni ipinle Ekiti.