Reuben Famuyibo: Aàrìn wa láwọn Ajínigbé wà, mo mọ ńkan tí màá ṣe nípa ẹ ní Ekiti
Awọn to sunmo gomina nikan lo n kọle ni Ekiti- Famuyibo
Oludije du ipo gomina ni ipinle Ekiti, Reuben Famuyibo ba BBC Yoruba sọrọ lori awọn nkan to ni lọkan lati se fun awọn eeyan ipinle Ekiti.
Oludije yii lo jade labẹ asia ẹgbẹ oselu Accord Party ni ipinle Ekiti.
- Àwọn gómìnà ilẹ̀ Yoruba kéde ọ̀fọ̀ ọlọ́jọ́ mẹ́ta lẹ́yìn ìkọlù tó mú ẹ̀mi èèyàn 40 lọ nílùú Owo
- Ojú ará oko, ojú ará òkè ni wọ́n fi ń wo àwa ará Ekiti, mo fẹ́ tún Ekiti ṣe ni- Debo Ranti Ajayi
- Ọlọ́run fẹ́ gbé Ekiti gorí ẹṣin ló ṣe ní kí ń díje gómìnà nínú ẹ́gbẹ́ ẹlẹ́ṣin - Segun Oni
- -Mo sá lọ sílé ìyàgbẹ́ nígbà tí agbébọn wọlé ìjọsìn àmọ́ wọ́n pa ìyá ìyá mi-
- Ìtẹ̀síwájú àwọn eèyàn Ekiti ló jẹ́ mi lógún- Kemi Elebute Halle
- Orangun: Ègún ni kí ǹkan wa má wù àwa gangan ti a ni ǹkan náà
- ₦2m ní Seyi Makinde ń fún Olopoeyan lọ́sẹ̀, wọ̀bìà ló mú kó kúrò nínú PDP - Auxillary
- 'Wọ́n sọ fún ìyà mi kó jù mi nù nígbà tí mò ń fi àyà fà bí ejò àmọ́ mo di àrídunú pẹ̀lú gbígbé "weight"