Ọ̀ràngún ti Ila: Èdè àti àṣà Yorùba ní láti jọ wá lójú fún ìdàgbàsókè ìran Yorùbá
Ọrangun ti ilu Oke Ila fi tinu tinu rẹ gba awọn ọmọ Yoruba nimọran lati ma jẹ ki aṣa adayeba wọn parun.
Bi aye ṣe n yi ti aṣa naa n ba a yi pẹlu, Ọba Adedokun Abolarin sọ pe bi a ba gbe aṣa larugẹ, yoo wu ajoji ati ara ilẹ okeere lori yoo si ya wọn lara lati fẹ mọ nipa aṣa wa sii.
- Ǹkan tí àwon omo Naijiria ń so nípa ''delegates'' tó ń dìbò fún egbé òsèlú ní yìí...
- Ìbànújẹ́ June 12 ti padà di ayọ̀ - Lekan Alabi
- A kò bèrè owó lọ́wọ́ ẹnikẹ́ni láti fòpin sí gbèǹdéke ìyanṣẹ́lódì – ASUU
- Kini 'pen' l'ede Yoruba?
- Ojú ará oko, ojú ará òkè ni wọ́n fi ń wo àwa ará Ekiti, mo fẹ́ tún Ekiti ṣe ni- Debo Ranti Ajayi
- Èrèdí tí mi ò ṣe ní ìbò kankan níbi ètò ìdìbò abẹ́nú APC l’Abuja rèé - Bakare