June 12: Lekan Alabi ní kí ọmọ Naijiria rántí àwọn akọni ìjọba àwa-arawa

Àkọlé fídíò, June 12: Lekan Alabi ní kí ọmọ Naijiria rántí àwọn akọni ìjọba àwa-arawa

Agbaakin Olubadan, Oloye Lekan Alabi ti ṣalaye bi ọrọ June 12 ṣe ri ni ọkan rẹ ati ọpọ ọmọ Naijiria lẹyin ti Aarẹ Muhammadu Buhari sọ June 12 di ayajọ ọjọ ijọba awa-arawa ni Naijiria lati yẹ MKO Abiola si.

Àwọn ìròyìn tí ẹ lè nífẹ̀ẹ́ sí: