Ekiti 2022: Bisi Kolawole sọ nínú ohun tó ṣetán láti ṣe fún àwọn ènìyàn Ekiti
Mo ti ba wọn ṣe e ri, àti mọ ibi ti iṣẹ ku si pẹlu iriri mi- Bisi Kolawole
Oloselu ni mi, mo mọ̀ iṣoro ara Ekiti ni kikun lori isoro awon eeyan Ekiti ati awọn nkan ti wọn n koju laisko yii.
Oludije Bisi Kolawole lo n dije labe asia ẹgbẹ oselu Peoples Democratic Party PDP.



