Local barbers vs Clipper: Ó pé mi láti lo abẹ fi fá orí mi ju "Clipper" bábà lọ
"Orí mi yóò dá kogbá kogbá lọ́dọ̀ àwọn fárífárí alábẹ, mi ò lè láyé láyé lo "clipper", bó ṣe owó gbọbọi, mo ṣe tán".
Aye atijọ la mọ pe wọn maa n fi abẹ fa ori amọ aṣa yii la ri pe o 'si tun wa laye ode oni ti ọpọ si yan lati maa lọ sọdọ awọn farifari alabẹ ju ki wọn lọ sọdọ awọn to n lọ ẹrọ igbalode fi bani gẹrun.
BBC Yoruba ba awọn alabẹ yii atawọn onibara wọn joko ti wọn si sọ idi ti wọn o file lọ si ṣọọbu oni "clipper" rara.
"Awọn mii wa to jẹ pe gbogbo ori wọn maa kun fun murumuru, latigba ti emi ti n wa sọdọ awọn alabẹ, ko si iru nkan to jọ bẹẹ".
- Mo Bimpe tú àṣírí bí Yomi ṣe ń nàá síí fún ìbalòpọ̀ lọ́pọ̀ ìgbà
- Ìkọlù DSS sílé Sunday Igboho tàpá sófin, ìwà ìjọba ológun ni - Falana
- Wo ohun tó le gbégi dínà àbádòfin tó wógilé ṣíṣàfihàn afurasí ọ̀daràn l'Eko
- Ìgbeyàwó òṣèrébìnrin mìràn tún forí ṣánpọ́n
- Ó di èèwọ̀ látí rán ọlọ́pàá, sójà, DSS wá sí ilẹ̀ Yoruba láì sọ̀ fún wa - Àpapọ̀ gómínà ní ilẹ̀ Yoruba
Iṣẹ to jẹ ọkan lara awọn iṣẹ aye atijọ nilẹ Yoruba yii ko fibẹẹ wọpọ lode oni tori imọ igbalode. Ọpọ awọn to n lọ sibẹ gbagbọ pe ọna atijọ ni amọ o tẹ awọn lọ run.
"Mi o wo ti owo rara, ti wọn ba fẹ gba ẹẹdẹgbẹrun naira, mo ṣe tan, mo maa n fẹ ki ori mi dan gbiinrin ko maa tan bii digi, ibi ni mo si ti le rii ṣe".
Ọkan lara wọn tilẹ jẹ ko di mimọ pe wọn o ki n ṣe nkan idọti rara. "Bileedi kan fun eeyan kan ni, wọn o si sọọnu bi wọn ba ṣe tan".
O ni oun tun fẹran gbogbo oogun apakokoro ti wọn maa n fi pa ori awọn ti wọn ba gẹrun fun.
amọ ko sohun ti ni didaa ti ko ni aidaa tirẹ, wọn ṣi mẹnu ba ọrọ imọtoto.
- Ìdí rèé tí àwa lọ́balọ́ba fi dákẹ́ lórí ìṣẹ̀lẹ̀ ìkọlù Sunday Igboho - Oluwo tí Iwo
- Wo àwọn gbajúmọ̀, òṣèré tó lọ sí ibi ètò ìsìnkú Temitope Joshua
- Odíndi mọ̀lẹ́bí kan jẹ́ oníbalòpọ̀ abo sí abo, wo irú ìpólówó ọjà wọn tó dá wàhálà sílẹ̀
- Kò jọọ́, adájọ wọ́gilé gbígba onídùró Dibu Ojerinde lórí ẹ̀sùn àjẹbánu ₦5.2 bílíọ̀nù ní JAMB
- Yomi Fabiyi, ìtíjú ńlá gbáà lo jẹ́ lórí fíímú ''Oko Iyabo'' tóo gbé jáde - Mercy Aigbe
- Ikú dóró! Lẹ́yìn ogún ọdún lórí ilẹ̀ alààyè, ẹṣin tó ga jùlọ Big Jake jáde láyé

