Coronavirus after one year in Nigeria: Níbo ni ọ̀rọ̀ Covid 19 dé dúró ní Nàìjíríà?
Lọjọ kẹtadinlogbọn, oṣu keji, ọdun 2020 ni Coronavirus wọle si Naijiria wẹrẹ.
Odun kan ree lẹyin iṣẹlẹ yii ni Naijiria.
Eeyan to le ni ẹgbẹrun 152, 000 lo ti kagbako coronavirus bayii ni Naijiria.
- Bí ìjọba ṣe ń pariwo "ẹ máa fọwọ́ yín tó", ẹ wo irú omi tí àwọn ará ìlú yìí fi ń fọwọ́
- Ṣé ojúlówó ni Oogùn apakòkòrò 'Sanitizer' tó ń lò? Wo bóo ṣe lè mọ̀ ayédèrú
- Ìjọba orílẹ̀-èdè Oman fòfin de Nàìjíríà àti orílẹ̀-èdè Mẹ́sàn míràn lati má wọ ìlú wọn
- Kí ni ìtumọ̀ àwọn alárùn covid-19 tí wọ́n ń pè ní ''Asymptomatic''?
Eeyan 1, 807 lo ti doloogbe lati ọwọ ajakalẹ arun yii ni Naijiria bayii.

Bẹẹ, ninu ewu ni awọn osisẹ eleto ilera n ṣiṣẹ ni Naijiria.
- Kíni àbájáde ìwádìí nípa báàjì àyà tí àwọn olóṣèlú kan ń wọ̀?
- Wo iye owó tó wọlé fún ìjọba lórí COVID-19 àti bí wọ́n ṣe ná an
- Àwọn alárùn coronavirus ṣe ìwọ́de ní Gombe, wọ́n ní ìjọba n febi pa wọ́n
- Ẹ wo ojú àwọn jàndùkú tí ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ nígbà tí wọ́n lọ kó ọjà ọlọ́jà ní Shoprite Ilorin
- Wo ohun mẹ́wàá tó yẹ kí o mọ̀ tí o bá fẹ́ lọ fún ìsinmi lẹ́yìn Covid 19
Ekọ wo lẹyin ti kọ nipasẹ ajakalẹ arun Covid 19 yii?

Titi di oni, ọjẹ kejdiinlọgbọn, oṣu keji, ọdun 2021, abẹrẹ ajẹsara lati gbogun ti ajakalẹ arun coronavirus ko i tii de si Naijiria.

- Ọ̀nà láti dín paǹtí irin kù ló sọ mí di agbẹ́rinlére aláṣeyọrí- Oladele Ogbeyemi
- Wo oríṣi oúnjẹ márùn ún tí kò wọ́pọ̀ ṣùgbọ́n tí àwọn kan fẹ́ràn púpọ̀ ní Nàìjíríà
- Ọ̀rọ̀ aàbò ní Nàìjíríà ti di kí olórí dorí ẹ mú- Femi Falana
- O lé rí ìrànwọ́ gbà lórí ìwà ipá nínú ìdílè àti ìfipábánilòpọ̀ nípasẹ̀ lílo UNSUB App