Coronavirus update: Kí ni ìtumọ̀ àwọn alárùn covid-19 tí wọ́n ń pè ní ''Asymptomatic''?
Iwadii ti fihan pe ida ọgọrin ninu ọgọrun awọn to laarun coronavirus ni kii ni ami tabi apẹrẹ to le fihan pe wọn ti laarun naa.
Iru awọn eeyan yii lawọn oloyinbo n pe ni ''Asymptomatic.''
Ewu to wa nibẹ ni pe iru awọn eeyan yii le ko aarun covid-19 ran ọpọlọpọ eniyan.
Ajọ WHO ni titakete si ara ẹni lo ṣe pataki bayii lati dena aarun covid-19.
- Bí mo ṣe ṣẹ́gun Coronavirus rèé - Seyi Makinde
- Coronavirus: Ọmọ márùn ún ni mo ní, ṣùgbọ́n kò sí oúnjẹ fún wa lásìkò ìgbélé yìí -Olùgbé ìlú Eko
- Èèyàn mẹ́fà míràn tún ti ní àrùn Coronavirus ní Naijiria
- Kí ló mú àwọn aládùúgbò Mọ́ṣáláṣí Alhaja kọlu àwọn ọlọ́ọpàá?
- Èyí ni ìdí tí coronavirus ṣe n pa àwọn kan, tí kò sì pa àwọn kan
- Coronavirus- Atọ́nà bí nkàn ṣe ń lọ ní Afirika