Coronavirus Update: Omi mímu wọ́n ju owó ilé lọ nílùú yìí

Àkọlé fídíò, 'A ò tíì rí omi mu, ẹ ní ká máa fọwọ́ tóríi Coronavirus'
Abule

Omi jẹ ọkan pataki lara ohun ti eeyan nilo bi yoo ba duro sile gẹgẹ bi ijọba ṣe n paṣẹ isede, ibomu, fifọwọ, diduro sile lasiko ajakal arun Coronavirus yii.

Bẹẹ si ni ọgọọrọ awọn araa apa Ila-Oorun Ariwa Afirika ti ko si larọwọto riri omi amọloolo lo n koju wahala bi arun naa ṣe n jẹ wọra sii bayii.

Ka to wi ka to fọ, ajọ eleto ilere lagbaaye, WHO yoo ti ni fifọ ọwọ loorekoore jẹ ohun akọkọ ninu gbigbena woju Covid-19.

Ẹwẹ, ni Naijiria ajọ kan ti ko rọgbọku le ijọba ti n kilọ pe lai si omi to mọ gaara, orilẹede Naijiria ko lee borii Coronavirus.

Eyi lo mu ki awọn ara ilu lẹkun Guusu Iwọ-Oorun, Guusu Iwọ-Oorun ati Ariwa Naijira figbe sita lorii iya ti wọn n jẹ leyii ti ijọba si n kigbe ẹ ma fọwọ loorekoore.

Awọn ara abule

Awọn iroyin ti ẹ le nifẹ si