World Water Day; Àwọn ara Ezeukwu ma ń rin ìrìn wakati méjì torí omi mímu
Awọn ara agbeegbe Ezeukwu ni ipinlẹ Abia ti sọ iriri wọn nipa wiwa omi to mọ lati lo nigba ẹrun.
Arabinrin Nnenna Anyim sọ wi pe o sọrọ fun awọn lati ri omi pọn, ti awọn tilẹ le rin irin wakati meji ki awọn to le ri omi ti awọn yoo lo nitori ko si omi mimọ ni agbeegbe naa.
Irin kilomita marun un ni wọn ma n rin ki wọn to tilẹ rin omi rara fun abọ fifọ, aṣọ fifọ ati lilo ninu ile.
- Njẹ́ jíjẹ́ aláwọ̀ dúdú le gbà ọ́ sílẹ̀ lọ́wọ́ ààrùn Coronavirus?
- Àfẹ́sọ́nà Davido, Chioma nàá ti ní ààrùn Coronavirus
- Fíímù ṣíṣe dáwọ́ dúró, Joke Muyiwa di 'grandma', Lizzy Anjorin sọ pé coronavirus ko gbọdọ̀ díwọ́ ọjà títà
- Ìjọba ìpínlẹ̀ Eko bẹ̀rẹ̀ pínpín oúnjẹ fún àwọn èèyàn lásìkò ìgbélé Coronavirus
Arabinrin Nnenna ni bi o tilẹ jẹ wi pe omi ti awọn n mu ko dara fun mimu, awọn ko i ti ni aisan nipa mimu omi naa ri.
Awọn ara agbeegbe Ezeukwu ni ipinlẹ Abia wa kesi ijọba lati ran awn lọwọ fun ipese omi mimọ to ṣe e mu ni agbeegbe naa.
Ẹkunrẹrẹ fidio yii ṣe afihan bi omi ti wọn n mu ṣe pupa, ti ko si yẹ fun mimu tabi lilo.