Coronavirus prevention badge update: Wo òótọ́ àti irọ́ tó wà nínú báàjì àyà náà

Àkọlé fídíò, coronavirus prevention badge update: Wo òótọ́ àti irọ́ tó wà nínú báàjì àyà náà

Awọn eeyan to lagbara pọ to n wọ baaji naa nitori pe wọn ko fẹ ni coronavirus.

Jeane Anez to jẹ aare fidihẹ orilẹ-ede Bolivia, Senatọ Dino Melaye, Ọmọọba Uche Secondus àti Dimtry Reskov to jẹ agbẹnusọ aarẹ Russia wa lara awọn oloselu ti wọn ti wọ baaji aya yii.

Wọn gbagbọ pe o n dena itankalẹ ajakalẹ arun Covid 19 ni wọn ṣe n wọ ọ.

Bẹẹ awọn akọṣẹmọṣẹ ni iro to jina si ootọ ni pe baaji naa n dena ajakalẹ arun coronavirus.

Koda, wọn ni o le fa nkan miran si agọ ara ẹni to wọọ.

Wo ẹkunrẹrẹ abọ iwadii naa lori fidio yii.