Ayansike: SS3 ní mo wà báyìí, mo sì ti gba àmì ẹ̀yẹ̀ púpò nílé-lóko gẹ́gẹ́ bí onílù
Ọmọbinrin awẹlẹwa to tun jẹ onilu, Ayansike ti sọ iriri rẹ lati igba to ti bẹrẹ si ni lu ilu lati ọmọ ọdun mejila.
Ayansike ni awọn obi oun ko kọkọ gba oun laaye pe ki oun maa lu ilu, amọ nigba ti wọn ri ifẹ ti oun ni si ilu lilu ni wọn gbaruku ti oun.
Ayansikẹ to n ṣẹ idanwo aṣekagba nilẹ iwe girama lọwọ, ti gba orisirisi ami ẹyẹ ni idi ilu lilu.
- Ọkọ mi bá àwọn ọmọ wa sọ̀rọ̀ lágo kan kó tó wọ bàálù tó já, àmọ háà! - Ìyàwó Olasunkanmi Olawunmi
- Wo ìlú mẹ́rìn-in tó ń bọ tàbí sin ejò bí ọlọ́run, ṣé ìlú rẹ̀ wà lára wọn tí o kò mọ̀?
- Sir Shina Peters ní ẹ ṣé, ìjà ti parí lórí ọ̀rọ̀ tó kan ọmọ olóògbé Funmi Martins; Damilare rẹ́rìín músẹ́ láì sọ̀rọ̀
- Kí ló ṣekú pa gbajúgbajà òṣèré Funmi Martins ìyá Mide-Martins lẹ́ni ọdún 38?
- "Orin Shanku, Gbese, Gbápa, Jesu máa párò lọ, inú Ọlọ́run kò dùn sí i - Bola Are
- Arapa re gangan sọ̀rọ̀ nípa ìrìnàjò ìpè rẹ̀ tuntun
- Wo àwọn ìlú tó jẹ́ pé ẹ̀ṣẹ̀ àti èèwọ̀ ni láti kú níbẹ̀
O gba awọn obi nimọran lati wa talẹnti ti awọn ọmọ ni, ki wọn si gbaruku ti wọn lati gbe ogo naa jade.
- Gbogbo àwọn Barrister, Kolington tó jẹ́ kòríkòsùn Ayinla Ọmowura, kò sí èyí táa rí nínú wọn' - Haruna, ọmọ Ayinla
- Ọba tó wàjà àmọ́ tí òkú rẹ̀ gbúdọ̀ jókòó sórí ìtẹ́ ṣáájú ìsìnkú
- Wo ìgbé àyé ìyá àti ọmọbìnrin tó ń fi iṣẹ́ aṣẹ́wó jẹun
- Èèmọ̀ wọ̀lú, agbébọn jí ajá tí iye rẹ̀ tó mílíọ̀nù 1,906,250.00 gbé lójú ìbọn, ó dèrò ilé ìwòsàn

