UNSUB App: Ṣé ó mọ́ ẹni tí wọ́n ti fipá bá lòpọ̀ rí tó ń fẹ́ ìdájọ́ òdodo?-Olajide Abiose
Koda, o le fi ẹjọ ifipabanilopọ rẹ lai jẹ ki a mọ iwọ gangan- UNSUB
UNSUB ni ẹro igbalode ti wọn ṣe lati din isọro obinrin ku lori ifipabanilopọ ati iwa ipa ninu ididle.
Ajọ The CANS lo ṣagbekalẹ rẹ pe ki ọkan awọn obinrin tun le balẹ sii ni awujọ wa.
- Ọ̀nà láti dín paǹtí irin kù ló sọ mí di agbẹ́rinlére aláṣeyọrí- Oladele Ogbeyemi
- Ṣé lóòtọ́ ni omidan yìí ya wèrè ní kété tí ọ̀rẹ́kùnrin rẹ̀ ní òun fẹ́ fi ṣaya?
- Akẹ́kọ̀ọ́ ọmọ ọdún mẹ́rìnlá mú ìbọn ìléwọ́ lọ ilé ìwé láti yìín lu olùkọ́ tó ní kó gé irun orí rẹ̀
- Kí ló mú kí géńdé Olorun fi àfọ́kù ìgò gé ǹkan ọmọkùnrin rẹ̀ ní Kano?
- Ọwọ́ pálábá Abubakar, mọ́káliíkì ségi níbi tó ti fẹ́ jí ọkọ̀ gbé l'Abuja
Olajide Abiose ni oludari ajọ naa to gbe eto iranlọwọ iwa ipa ninu idile yii kalẹ.
Ajọ NHRC naa ba wọn fọwọsọwọpọ ki awọn ẹtọ obinrin le maa jade.

Oju awọn eeyan ti n ṣi si ọna abayọ lati fẹsun kan sibi to yẹ nigba ti iwa ipa ba ṣẹlẹ nibikibi ni Naijiria.
Wo diẹ lara ohun ti imọ ẹrọ UNSUB le ṣe fun ẹ lori foonu re:
- O le fẹsun kan ẹni to ba ni lo pọ pẹlu ipa
- O le lo o lati se e fun ẹlomiran ti ko le sọrọ.

- O le fi ara pamọ laijẹ ki ẹnikẹni mọ pe iwọ lo ṣẹlẹ si.
- O le sọ ibi to ti ṣẹlẹ nikan
- O le tun ṣe fọnran fidio bo ṣe ṣẹlẹ ati bẹẹ bẹẹ lọ.
- Olajide Abiose ni eyan to le ni igba lo ti jẹ anfani imọ ẹro UNSUB yii ti wọn si ti ri iranlọwọ gba.



