BBC findings on lekki shooting: Ẹ wa wo àwọn tó ṣì ń wá ẹbí wọn nínú ìṣẹ̀lẹ̀ End SARS 2020
Onikaluku sọ ohun ti oju wọn ri.
BBC safihan ẹri ti iwadii fidi ẹ mulẹ lori ohun to ṣẹlẹ ni Lekki Toll Gate ni ipinlẹ eko lalẹ ogunjọ oṣu kẹwaa, ọdun 2020 nibi iwode End SARS.
Iwọde yii ni àwọn ọmọ Naijiria ṣe lodi si ifiyajẹni lọna aitọ awọn agbofinro.
Lẹyin eyi ti ijọba Naijiria fi ofin de awọn ọlọpaa kogberegbe SARS ti wọn si tun ṣagbekalẹ SWAT.
- MC Oluọmọ gbé ara rẹ̀ ṣépè nítorí ìwọ́de #ENDSARS
- Àwọn ọmọ Naijiria kó owó wọn kúrò ní Access Bank lẹ́yìn tó gbẹ́sẹ̀lé àpò owó àwọn olùwọ́de EndSARS
- Gbọ́ ìtàn bí ikọ̀ SARS ṣe dà bó ṣe dà láti ẹnu Ọ̀gá ọlọ́pàá tó dá SARS sílẹ̀
- Buhari kò láànú ọmọ Nàìjíríà lójú - Aisha Yesufu
- Àrùn ń bẹ lóde, ẹ̀yin olùwọ́de EndSARS, ẹ ṣọ́ra fún Covid-19 - Ìjọba àpapọ̀ kìlọ̀

- Wo ìsọ̀rí àwọn tó jẹ́ kí ìwọ́de End SARS / end SWAT lárinrin àti ìtumọ̀
- 'Ó ku ọ̀la kí Isiaka ṣe 'Freedom' ní àṣìta ìbọn bà á ní Ogbomọshọ '
- Omijé fẹ́ bọ́ lójú mi tí mo bá ṣàfiwé SARS tí mo dá sílẹ̀ àti SARS tó wà níta báyìí- Fulani Kwajafa
- "A ti já gbogbo ojú òpó ìjọba Nàìjíríà gbà lórí Twitter láti ṣàtìlẹyìn ìwọ́de End SARS" - Anonymous



