Dambe fight: ìdíje ìjà láàrin àwọn akóni tó n ja ẹ̀ṣẹ̀
Indonesia, Phillipines àti America ni wọn ti n wo ija Dambe ju lagbaye.
Nile Hausa ni ija Dambẹ ti wọpọ julọ gẹgẹ bi ere idaraya laarin wọn.
Bahagon Ango Argungun jẹ ọkan lara aọn to maa n saaba kopa ninu idije ija Dambe
Anthony Okeleke ati Chidi anyanwu ti wọn jẹ agbatẹru ija Dambe yii ni o le ni miliọnu mẹrinlelogun awọn eeyan to maa n tẹle awọn idije yii lori ayelujara
O gbọdọ kan alatako rẹ lẹṣẹ mọlẹ ki o ṣubu ki o to le bori ninu idije ija Dambẹ ni.
Awọn eniyan orilẹ-ede Indonesia, Philipines, America ati bẹẹ bẹẹ lọ lo maa n wora ija Dambẹ julọ lori ayelujara.