Olutayo Amokade: 'Ẹ má boore Ọlọ́run mọ́ra; Ti mo bá ra ilé lọ́la màá gbé sórí ayélujára'
'Ìjẹ̀bú tó ya wèrè gan an ni mí o'
Gbajugbaja òṣeré Yollywood, Olutayọ Amọkade ti gbogbo ayé mọ̀ sí Ijẹbu rọ àwọn èèyàn láti ma bẹ̀rù idojukọ rara.
O ni ipenija maa n sọ eeyan di ológo ni lọjọ ọ̀la.
O ni: mo ti ṣiṣẹ ọjọ meje ri fún ọọdunrun naira péré (N300) nigba ti mo ṣi n ṣe generator man' iyẹn awọn oṣiṣẹ amunawa to n fa ina fun lilo ni òde eré.
- Ààrẹ Mozambique tẹ́lẹ̀ rí jẹ́jọ́ lórí ẹ̀sùn ìwà ìbàjẹ́ tí wọ́n fi kan ọmọ rẹ̀
- Ìyá ẹni ọdún 102 kéde ìpinnu rẹ̀ láti díje du ipò Ààrẹ Naijiria lọ́dún 2023
- Ẹnikẹ́ni tó bá tún fi ìyà jẹ òṣìṣẹ́ LASTMA l'Eko yóò fojú winá òfin- Ọ̀gá LASTMA
- Yàtọ̀ sí Bimbo Success àti Kemi Korede, wo àwọn míì tí wọ́n ń pariwo Funke Akindele kiri
- Àwọn òṣìṣẹ́ wa kò lọ́wọ́ nínú gbígbé egbògi olóró - NDLEA
- Ìjọba ìpínlẹ̀ Kogi buwọ́lu ₦30,000 owó oṣù òṣìṣẹ́ tó kéré jùlọ
- Àwọn ti a jọ ń 'robb' lo pa Ìyá mi sínú ẹ̀jẹ̀ ní 'Mission House'- Alufaa Oluwasegunfunmi
Kini ero Ijebu lori awọn oṣere to n ja lori ayelujara?
Ijẹbu ni ọjà lasan ni àwọn oṣere Yollywood paapaa àwọn obinrin n fi ìjà lori ayelujara ṣe.
O ni wón kan ń fi kun orukọ lasan ni.
O gbà pe Ọlọrun lo ni ògo to maa n fun onikaluku nigba ti asiko ba yẹ.
- 'Ǹkan tó jẹ́ kí iṣẹ́ ọ̀nà tèmi yàtọ̀ lágbàáyé ni ǹkan tí mò ń lò'
- Mí o mọ̀ pé ikú ni 'Distinction' tí OAU ni fún ọmọ mi Heritage- Ìyá ọmọ tó jábọ́ sí 'Soak away'ní Ife
- Igi ẹ̀fọ́, ojú ẹlẹ́gba àti oríṣi orúkọ̀ míì ní wọ́n ń pè mí nítorí pé Òbí mi kọlà sí ojú mi- Damilola
- Eló ló lè mú ọ kópa nínú idíje ata jíjẹ?
- Ọjọ́ tí ọlọ́pàá mú mi kó mi láyà sókè, n kò le gbàgbé láéláé - Bad Boy Timz
- Wọ́n fún mi ní ‘Biscuit’ jẹ ní òde àṣé Igbó ni, inú gbọ̀ngàn ayẹyẹ wá dàbí ebè lójú mi – Olaiya Igwe