Àwọn ti a jọ ń 'robb' lo pa Ìyá mi sínú ẹ̀jẹ̀ ní 'Mission House'- Alufaa Oluwasegunfunmi
Nkan ki si ẹsẹ rago ni ọrọ irinajo Alufaa Oluwasegunfunmi Oluwashinaayo.
Airinjinna ni eeyan a ni oun ko ri abuke ọkẹrẹ ri, ti eeyan ba rin jinna, o di dandan ko ri ekute ile to ni idodo.
Alufaa yii ti di alakoso ijọ nla ninu ile ijọsin Christ Apostolic Church.
BBC mu irinajo Alufaa yii wa ki awọn Obi ati ọdọ asiko yii le kọ ẹkọ.
- Itan omi gbigbona ati tutu ni Ikọgosi Ekiti
- Mọ̀ sí i nípa Oba Yesufu Asanike, Olubadan tí kìí fi ọ̀rọ̀ sí abẹ́ ahọ́n sọ kódà níwájú sọ́jà
- Àwọn obìnrin ológun tó kojú àwọn amunisin nílẹ̀ Áfríkà
- Ìtàn nípa orúkọ àdúgbò tó níí ṣe pẹ̀lú ìjà Oyo, Fulani àti Ilorin ní 1835
- Ìdí tí wọn kii fi jẹ́ kí obìnrin jẹ Ọ̀ọ̀ni ni Ile Ife
- Ìtàn ọ̀rẹ́ tó fi òògùn gba ọkọ ọ̀rẹ́ rẹ̀ ni Akomolede BBC Yorùbá fẹ́ kọ́ wa lònìí
- 'Òǹtàjà aṣọ ni mí tẹ́lẹ̀, ọ̀dá owó ló sọ mi di alábárù'
Die nipa ohun to ṣẹlẹ si Alufa Oluwashinaayomi Oluwasegunfunmi ree:
Omo Alufaa ati Iya agbebi ni ti wọn si fi ilana ẹsin Kristieni kọọ bo ṣe yẹ.
Ile Eko Fasiti lo wọ lati lọ kọ nipa iṣẹ iṣegun oyinbo ki ẹni ti wọn jọ n gbe ile to yii lọkan pada to wọ ẹgbẹ okunkun lo.
Bẹẹ, gbogbo ẹbi ati ara lo da owo ile ẹkọ giga fun Oluwasegunfunmi lati fi ran Obi rẹ lọwọ.
- Obinrin kan rèé tó borí ogun Gẹ̀ẹ́sì
- Ọba Lamidi Adeyẹmi, òṣìṣẹ́ adójútòfò àti Abẹ̀ṣẹ́kùbíòjò kó tó jọba
- Ṣé ìwọ mọ ìtàn Ibadan àti ìgbín mẹ́rin? ipá wo ni Abuké àti Àfín kó nínú ìtàn Ibadan?
- Ṣé ìwọ mọ ìtàn Ọdẹ tó tẹ Ẹ̀pẹ́ dó láti ìgbà ìwásẹ̀?
- 'Ohùn tí mo ṣe ní fásitì tó mú mi gba "Distinction 10", àmi ẹ̀yẹ̀ 5, ilé ọ̀fẹ́ àti owó tabua rèé'
- Wo ìtàn bí ààlọ́ ṣe bẹ̀rẹ̀ àti onírúurú ààlọ́ àpagbè àti àpamọ̀
- Alimotu Pelewura, Ìyálọ́jà akọ́kọ́ l’Eko tó mi amúnisìn àti ìjọba tìtì
Wo awọn iwa ti ọdọkunrin yii hu loriṣiiriṣi ki o to ba Jesu pade gangan ti o si wa di ajihinrere to n waasu iyipada ọkan kiri bayii.
Mọ sii nipa awọn aṣiṣe Obi to yẹ ki o kẹkọọ nipa rẹ ninu fọran fidio naa.




