E jẹ́ ká lọ sí ìlú mi BBC yìí dá lórí Epe ní bi tí eégún ti ń fi ẹgba dá bírà lára Oba

Àkọlé fídíò, E jẹ́ ká lọ sí ìlú mi BBC yìí dá lórí Epe ní bi tí eégún ti ń fi ẹgba dá bírà lára Oba

Wa mọ sii nipa Epe Ijebu ati Epe Eko

Eto ẹ ka lo si ilu mi ni ilu Epe ni BC Yoruba gbe wa lọsẹ yii.

Epe lo ni ẹja ati awọn ẹranko omi to pọ ni jijẹ.

Wo oríṣi ẹja tó kún ìlú Epe ní ìpínlẹ̀ Eko.

Epe

Se ẹ ranti ayaba Sheba tó ṣabẹ̀wò sí Oba Solomoni nínú Bibélì?

Epe

Wo ibi tó gbé ní Epe rí kó tó lọ sí Oke Ẹri ní Ijẹbu Ode.

Epe

Waheed Agbomeji sọ itan bii Bilikisu ṣe gbe ni Epe.

Alahji Waheed salaye kikun lori bi o ṣe kuro ni epe ati awọn ibi to tun lọ ki ọlọjọ to de.

Epe

Wa mọ ipa ti Oba Kosoko ko nipa itan Epe

Wo awọn Oba to ti jẹ ni Epe.

Epe

Oba Shefiu Olatunji Adewale pa itan bi Epe ṣe bẹrẹ bẹẹ ẹnu agba lobi ti n gbo.

Epe

Oba Olufolarin Ogunsanwo ti Ilara Epe salaye ipo pataki ti alara n ko ninu itan Epe.

Epe

Bakan naa ni Ooni Adeyey Enitan Ogunwusi mẹnuba itan Ilara mokin, Ilara moko ati Ilara Epe .

Epe

O so nipa odu Ogbe Alara to jẹ Ogbe Iyeku meji to da wọn silẹ pẹlu adura.

Epe

Wo igbesẹ inu ọdun Kilajolu nibi ti eegunti n na Kabiesi ko to gabdura fun ara ilu.

Epe