Oduduwa Alphabet: Wo àwọn ibùdó mánigbàgbé tó wà ní Ajaṣe ni oriléèdè Benin Republic níbi tí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ Yorùbá ti lọ ṣàbẹ̀wò

Opọlọpọ awọn akẹkọo Yoruba lo lọ si Ajaṣẹ laisko ikẹkọgboye Alifabẹẹti Oduduwa nibi ti wọn ti lọ mọ si nipa iran Yoruba to wa nibẹ.

Oduduwa Alphabet
Àkọlé àwòrán, Aafin Oba Ajaṣẹ ni orilẹ-ede Benin Republic
Oduduwa Alphabet
Àkọlé àwòrán, Ere ọkan lara awọn Oba ana ni ilu Ajase
Oduduwa Alphabet
Àkọlé àwòrán, Oloye Toluwalase to jẹ Oludasile ile ẹkọ́ to n kọ ni nipa Alifabẹẹti Oduduwa
Oduduwa Alphabet
Àkọlé àwòrán, Abesan
Oduduwa Alphabet
Àkọlé àwòrán, Aye Oga-gba-Mi nibi ti wọn ri Akapo mọ laaye
Oduduwa Alphabet
Àkọlé àwòrán, Oloye Toluwalase ati die lara awọn akẹkọọ to wa lati awọn ile ẹkọ giga Naijiria wa ṣabẹwo si awọn ibudo iṣẹmbaye ni Ajaṣẹ
Oduduwa Alphabet
Àkọlé àwòrán, Igi to le awón osise 'Ministry' kuro nigba ti wọn lọ kọ ọọfiisi wọn si nibẹ lẹẹmẹta.
Oduduwa Alphabet
Àkọlé àwòrán, Kabiesi Abesan ni ilu Ajase ni roile ede Benin Republic to gab awọn akẹkóọ Naijiria naa lalejo wa wo orisun ti awọn ọmọ Yoruba Ajase po si
Oduduwa Alphabet
Àkọlé àwòrán, Igi to le awọn eeyan kuro ninu igbo naa lẹẹmẹta ọtọọtọ ni Ajaṣẹ
Oduduwa Alphabet
Àkọlé àwòrán, Oloye Popo niwaju igi to le awọn eniyan kuro ninu igbo naa ti o si di eyi ti wọn n bọ bayii ni ilu Ajase ni orile-ede Benin Republic.
Oduduwa Alphabet
Àkọlé àwòrán, Igi Aramonda to n dara to wu u ninu igbo naa ni Ajaṣe ni orilẹ-ede Benin Republic