Ọlatunbọsun Blessing Damilọla: Ẹ dẹkún fífi ẹni tó bá kọ ilà sójú ṣe yẹ̀yẹ́ láwùjọ

Àkọlé fídíò, Damilọla pàdánù ọ̀rẹ́kùnrin rẹ̀ nítorí ilà kíkọ

Ojú tí àwọn ọmọ Nàìjíríà fi ń wo ilà kíkọ.

Àwọn míì máa ń pè mí ní nọmba 11

Ọlatunbọsun Blessing Damilọla sọ ìrírí rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ènìyàn nítorí pé ọ̀kọlà ni.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ sí:

Bakan naa ni BBC ba Obi Damilola ṣorọ, wọn si ṣalaye idi ti wọn fi kọla fun ọmọ wọn nigba naa.